Àtẹ́lẹwọ́

…ìràpadà, ìsọjí, ìtúntò

  • Ojúde-Àkọ́kàn
  • Ìgbàwọlé
  • Ewì
  • Àpilẹ̀kọ
  • Eré
  • Àwòrán
  • Ìtàn
  • Ìròyìn
  • Àṣàyàn Olóòtú

Àṣàyàn Olóòtú

Home /Àṣàyàn Olóòtú
Àpilẹ̀kọ

Ẹni Bá Ń Yọ́lẹ̀ Ẹ́ Dà | Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀

March 10, 2023 0

Òru là ń ṣèkà ẹni tó ṣe lọ́sàn-án kò fara rere lọ. Ilẹ̀ ti ta sí i ti àwọn ọmọ wòlìbísà tí ń ja àwọn…

Àṣàyàn Olóòtú

Ogún ìní mi | Bákàrè Wahab Táíwò

February 25, 2023 1

Nígbà mo wà lọ́mọ ọwọ́ Mo gbájú métè ìyáà mi korokoro Nígbà mo wà pẹ̀lú bàbá èmi Mo wòye ìsọ̀rọ̀sí rẹ̀ Mo wẹnu àwọn tí…

Àpilẹ̀kọ

Láyíwọlá Ẹkùn Ọkọ Òkè | Ọláyínká Opanike

February 25, 2023 0

Láyíwọlá ò sẹ̀sẹ̀ máa f’ẹ́wọ́. Ògbóntarìgì olè ni. Kìí ṣe ọlọ́sà rárá o. Tó bá ti kọjáa àfọwọ́rá, kìí bá wọn gbèro rẹ̀. Fún Láyíwọlá…

Àṣàyàn Olóòtú

Ẹ Wí Fún Ikú | Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀Ẹ Wi Fún Ikú |

February 25, 2023 1

Ẹni tó bá mọ àlùmúńtù Ẹ bá mi wá a lọ, a ní gbólóhùn Ẹni tó bá mọ abà tí ikú ń gbé Ẹ bá…

Àṣàyàn Olóòtú

Káṣílẹ́sí  Pọlisì (Cash-Less Policy) | Akíntọ́lá Ismail Kọ́ládé

February 25, 2023 1

Ìlú kan gógó, Ilu òf'ara rọ Àwọn ará ìlú gaan ò rẹ́ẹ̀rín. Àṣe k'árówóná òdàbí k'álówó nílé k'álówó nílé gan-an òdàbí k’álówó lápò k’álówó lápò…

Àṣàyàn Olóòtú

Ọ̀rọ̀ Olóòtú: A kú Ọdún o!

February 25, 2023 0

Ẹ kú u dédé àsìkò yìí o ẹ̀yin òǹkàwé wa, a sì kú ọdún tuntun. Ọdún ayọ̀ ni yóò jẹ́ fún wa, ọ̀pọ̀ ọdún la…

Aáyan ògbufọ̀

Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú | Olúwáfẹ́mi Kẹ́hìndé Lawrence

December 23, 2022 0

Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú / On Death Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú I. Ǹjẹ́ ikú le è jẹ́ orun bí, kí ayé sì jẹ́ àlá? Kí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀…

Àpilẹ̀kọ

Ẹ Fẹ̀yí Kọ́gbọ́n | Bákàrè Wahab Táíwò

December 23, 2022 0

Ẹ Fèyí Kọ́gbọ́n Mo délé Alárá N ò gbọ́ poroporo odó Mo délé Ajerò N ò gbọ́ kọ̀ǹkọ̀ṣọ̀ ajọ̀ Mo délé Ọwárọ̀gún-àga Bákan náà lọmọọ́…

Àpilẹ̀kọ

Àlàmú Olókùn | Ọláyàtọ̀ Ọláolúwa

December 17, 2022 0

Àlàmú Olókùn Ọ̀kan lára awọn ẹranko tí ó kéré jùlọ ni Aláǹtakùn (a-lá-rìn-ta-okùn-mọ́lẹ̀), bí ó bá ń rìn, yóò máa ta okùn mọ́lẹ̀, ìdí nìyí…

Àṣàyàn Olóòtú

Ọ̀rọ̀ Láti Ọ̀dọ̀ Olóòtú — Ìpalẹ̀mọ́ Pọ̀pọ̀ṣìnṣìn Ọdún

November 17, 2022 0

Ẹ̀yin Ònkàwé, Ẹ kú u dédé àsìkò yìí o ẹ̀yin òǹkàwé wa, a sì kú ìpalẹ̀mọ́ pọ̀pọ̀ṣìnṣìn odún tuntun tó ń bọ̀ lọ́nà. Èyí ni…

Posts navigation

1 2 … 6 next

ÀTẸ́LẸWỌ́

ÀTẸ́LẸWỌ́ jẹ́ àjọ tí ò wà láti gbé Yorùbá dìde àti láti tún iṣẹ́ Yorùbá tò. Àwọn àfojúsùn wa jẹ́: 1. Láti pèṣè ibi tí àwọn akẹ́kọ̀ ati ọ̀dọ́ leé máa kopa pẹlú oríṣiríṣi ẹya aṣa àti ìṣe Yorùbá látàrí ìdíje, ẹ̀kọ́, ìfọ̀rọ̀jomítoro ọ̀rọ̀ ati ṣi ṣe ìpàdé déédé. 2. Láti ṣe àgbékalẹ̀ ibi tí a ti má ṣe àkọsílẹ̀ ati ìpamọ òye àṣà Yorùbá ìgbà àtẹ̀yìnwá àti láti máá lo ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé fún ìdàgbàsókè àṣà wa. 3. Tí ta àwọn èyàn jí sí ìfẹ́ lítíreṣọ̀ Yorùbá latàrí ṣiṣe ètò ìwé kíkà, jíjẹ kí ìwé lítíreṣọ̀ Yorùbá wà nlẹ̀ fún tità àti ṣíṣe àtẹ̀jade àwọn oǹkọ̀wé titun ní èdè Yorùbá.


Contact us: egbeatelewo@gmail.com

  • Ilé
  • Nípa Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìdíje Ìwé Kíkọ
  • Ikọ̀
  • Àtẹ̀jáde
  • Ètò Ìwé Kíkà
  • Ògbóǹtarìgì: A Docuseries Project to Celebrate Old Veteran Yorùbá Authors
  • Kíni Wọ́n ń Sọ
  • Ètò
  • Ẹ kàn sí wa
  • Aáyan ògbufọ̀
  • Àpilẹ̀kọ
  • Àṣàyàn Olóòtú
  • Àwòrán
  • Eré
  • Ewì
  • Fídíò
  • Ìròyìn
  • Ìtàn
  • Ìtàn Àròsọ
  • Ìtọ́wò Ìwé Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìwádìí
  • Lẹ́tà
  • News
  • Orin
  • Rìfíù Ìwé
  • Uncategorized