ÀTẸ́LẸWỌ́ PÉLÉBÉ

Tí àwọn ònkọ̀wé mejìdínlógójì bá parapọ̀ láti kọ lórí àṣà, àgbègbè, òṣèlú, ìwòsàn, ènìyàn, ìwà, ìfẹ́, àbò, ẹwà abbl ǹkan tó yẹ a màá retí ní ìwé Atẹlẹwọ Pélébé – àkójọpọ̀ èrò ní èdè Yorùbá.

Iyé = 500 Naira

Ó wà lori OKADABOOKS.

Ẹ sì tún le ra PDF ìwé naa dàrẹẹtì lọwọ wa ti à ó sì sẹ́ndì rẹ̀ sí méélì yín tabi WhatsApp.

Ẹ tiransifa àpò méjì àbọ̀ (N500) si àkántì yìí:

ATELEWO CULTURE AND LANGUAGE SERVICES  

1021878832

UBA

Ẹ Sẹ́ndì arídájú tiransifa naa sí egbeatelewo@gmail.com tàbí 07061282516 (WhatsApp) à ó sì sẹ́ndì kọ́pì yín ní kía kía.