Ayé yìí ò le Pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ lejò ń gàgbọn. Ayé yìí ò gba gìrìgìrì Lọ̀gà fi ń tẹlẹ̀ jẹ́jẹ́jẹ́. Ẹ̀sọ̀ pẹ̀lẹ́ ló láyé Dúníyàn ò fẹ́…
ẸFÚNṢETÁN Ọya ṣe tán ó rà sílé 'rá Ṣàngó ṣe tán ó wọlẹ̀ní Kòso Ẹfún ṣe tán ó lójú orógbó Ẹfun ṣe tán ó wẹwù…
Nígbà mo wà lọ́mọ ọwọ́ Mo gbájú métè ìyáà mi korokoro Nígbà mo wà pẹ̀lú bàbá èmi Mo wòye ìsọ̀rọ̀sí rẹ̀ Mo wẹnu àwọn tí…
Ẹni tó bá mọ àlùmúńtù Ẹ bá mi wá a lọ, a ní gbólóhùn Ẹni tó bá mọ abà tí ikú ń gbé Ẹ bá…
Ìlú kan gógó, Ilu òf'ara rọ Àwọn ará ìlú gaan ò rẹ́ẹ̀rín. Àṣe k'árówóná òdàbí k'álówó nílé k'álówó nílé gan-an òdàbí k’álówó lápò k’álówó lápò…
Oore Ló Pé Oore ló pé Ẹ jẹ́ á ṣoore Ìkà ò pé Gbogbo Mùtúnmùwà! Bó o bá ṣe é ree Wà á kẹ́san À’tore…
Ẹ Fèyí Kọ́gbọ́n Mo délé Alárá N ò gbọ́ poroporo odó Mo délé Ajerò N ò gbọ́ kọ̀ǹkọ̀ṣọ̀ ajọ̀ Mo délé Ọwárọ̀gún-àga Bákan náà lọmọọ́…
Àyàjọ́ Falẹ! À ń gbòròmọdiẹ lọ́wọ́ ikú Tonídìí ní í dà nígbẹ̀yìn bídìí bàjẹ́ Ó tún ti ṣẹ̀ bó ti ń sẹ̀ Ó tún ti…
Ìwé Le! Túlẹ̀, ẹ sáré wá Akẹ́kọ̀ọ́, ẹ wá gbọ́ nàsíà Òkun kì í hó ruru Ká wà á ruru, àwé! Ìwé le lorin tí…
Agbẹ́kẹ̀lé Ènìyàn Mo gbọ́ pé ayé wà Mo múra èrò ìjìnlẹ̀ Mo rí i pẹ́dàá ń ráyé lò Mo múra, ó di dúnníyàn Mo wá…