À-pè-kánukò Àpèkánukò! Àpèṣ'ẹnu ṣùùtì Bí-i músù ú rẹ́ja nínú ike. Owó ní í jẹ́bẹ̀, ìwọ ọ̀rẹ́, Bí kò bá sí nílé, Ẹ má wúlẹ̀ d'ọ́rọ̀…
Kíkorò Ewúro Gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Adùn ló yẹ kí ó gbẹ̀yìn ewúro Ṣùgbọ́n kò sẹ́ni tí ó ń Bèrè nípa kíkorò tí ewúro…
Nínú ọ̀rọ̀ ìṣáájú fún ìwé ‘Adéjọké ará Ìjílèje—Àkójọpọ̀ ìtàn kéékèèké Adébáyọ Fálétí,’ Òjọgbọ́n Ọlátúndé O. Ọlátúnjí kọ wípé: “Àwọn ọmọdé ni Adébáyọ Fálétí fi perí…
A dúpẹ́ fún àwọn ohun tí ẹ fi ṣowọ́ sí wa fun àtẹ̀jade Kínní. Àtẹ̀jade kejì yíò jẹ́ ìfisorí fún àwọn àgbà oǹkọ̀wé mẹ́ta tí…
Ní ojoojúmọ́ ayé mi ni mo máá ń ronú nípa ayé àwa ẹ̀dá, nípa àditú ayé tí ó ń fi ìgbà gbogbo ṣ’emí ní kàyéfì.…
Ṣèbí oun tí mo mọ̀n tí wọ́n má ń sọ ni pé òkùnkùn kìí bórí ìmọ́lẹ̀, pé irọ́ kìí jáwé borí òtítọ́, pé rìkíṣí kìí…
Ìwọ̀n ẹni là á mọ̀, A kì í mọ tẹni ẹlẹ́ni. Bí a ò bá ronú àti bùkèlè, Ó ṣe é ṣe ká jẹwọ móúnjẹ́.…
Wón ní, Ikú ogun ló ń pa akíkanjú Ikú odò lo ń p’òmùwẹ̀ Ikú ẹwà ni wón ní ó ń pa egbin Ikú abo ló…
Ó kúkú ti pẹ́ tí Náírà ti ń gbọ́ nípa Kọ́bọ̀. Kódà ìtàn sọ fun u pé gẹ́lẹ́ tí Náírà gbòde şóun ni Kọ́bọ̀ doun…
È̩RÍN ÀRÍNTÀKÌTÌ L’ÉKÌTÌ Ìpínlè̩ Èkìtì jé̩ ò̩kan pàtàkì lára àwo̩n ìpínlè̩ t íÌjo̩ba Ológun dásílè̩ ní 1996 lábé̩ ìs̩è jo̩ba Ò̩gágun Sanni Abacha. Láti ara…