Nígbà mo wà lọ́mọ ọwọ́ Mo gbájú métè ìyáà mi korokoro Nígbà mo wà pẹ̀lú bàbá èmi Mo wòye ìsọ̀rọ̀sí rẹ̀ Mo wẹnu àwọn tí…
Láyíwọlá ò sẹ̀sẹ̀ máa f’ẹ́wọ́. Ògbóntarìgì olè ni. Kìí ṣe ọlọ́sà rárá o. Tó bá ti kọjáa àfọwọ́rá, kìí bá wọn gbèro rẹ̀. Fún Láyíwọlá…
Ẹni tó bá mọ àlùmúńtù Ẹ bá mi wá a lọ, a ní gbólóhùn Ẹni tó bá mọ abà tí ikú ń gbé Ẹ bá…
Ìlú kan gógó, Ilu òf'ara rọ Àwọn ará ìlú gaan ò rẹ́ẹ̀rín. Àṣe k'árówóná òdàbí k'álówó nílé k'álówó nílé gan-an òdàbí k’álówó lápò k’álówó lápò…
Ẹ kú u dédé àsìkò yìí o ẹ̀yin òǹkàwé wa, a sì kú ọdún tuntun. Ọdún ayọ̀ ni yóò jẹ́ fún wa, ọ̀pọ̀ ọdún la…
Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú / On Death Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú I. Ǹjẹ́ ikú le è jẹ́ orun bí, kí ayé sì jẹ́ àlá? Kí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀…
Ẹ Fèyí Kọ́gbọ́n Mo délé Alárá N ò gbọ́ poroporo odó Mo délé Ajerò N ò gbọ́ kọ̀ǹkọ̀ṣọ̀ ajọ̀ Mo délé Ọwárọ̀gún-àga Bákan náà lọmọọ́…
Àlàmú Olókùn Ọ̀kan lára awọn ẹranko tí ó kéré jùlọ ni Aláǹtakùn (a-lá-rìn-ta-okùn-mọ́lẹ̀), bí ó bá ń rìn, yóò máa ta okùn mọ́lẹ̀, ìdí nìyí…
Ẹ̀yin Ònkàwé, Ẹ kú u dédé àsìkò yìí o ẹ̀yin òǹkàwé wa, a sì kú ìpalẹ̀mọ́ pọ̀pọ̀ṣìnṣìn odún tuntun tó ń bọ̀ lọ́nà. Èyí ni…
Mi ò rántí ìgbà tí mo kọ́kọ́ gbọ́ gbólóhùn “Ọlọ́jọ́” nínú ọ̀rọ̀, àmọ́ mo rántí wípé nígbà èwe mi, tí àwọn èèyàn bá sọ wípé,…