Àwọn Ìwé àti Dáyáàrì Sálù Jẹ́nwítèmi | ‘Gbénga Adéọba
I Ènìyàn bí reluwé ni Alàgbà Sálù Jẹ́nwítèmi; kò ṣeé kọlù, bẹ́ẹ̀ni kò sì gbọ́dọ̀ kọlu ènìyàn. Kì í see […]
I Ènìyàn bí reluwé ni Alàgbà Sálù Jẹ́nwítèmi; kò ṣeé kọlù, bẹ́ẹ̀ni kò sì gbọ́dọ̀ kọlu ènìyàn. Kì í see […]
Nígbà kan rí, àwọn ẹranko kéréjekéréje bi Eèrà, Ìjàlọ, Eku, Aáyán, Ikán àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ yan Ìjàlọ kó máa
Ẹni tí yóò bá pẹ̀gàn àjànàkú ni yóò sọ pé òun rí nǹkan fìrí. Igi pọ̀ nígbó àmọ́ ọ̀tọ̀ ni
Òru là ń ṣèkà ẹni tó ṣe lọ́sàn-án kò fara rere lọ. Ilẹ̀ ti ta sí i ti àwọn ọmọ
Láyíwọlá ò sẹ̀sẹ̀ máa f’ẹ́wọ́. Ògbóntarìgì olè ni. Kìí ṣe ọlọ́sà rárá o. Tó bá ti kọjáa àfọwọ́rá, kìí bá
Oore Ló Pé Oore ló pé Ẹ jẹ́ á ṣoore Ìkà ò pé Gbogbo Mùtúnmùwà! Bó o bá ṣe é
Tata Àti Ìrẹ̀: Ẹranko Olóhùn Tó Bá Ìgbà Mu / On The Grasshopper And Cricket Ewì inú Ayé ò kú
Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú / On Death Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú I. Ǹjẹ́ ikú le è jẹ́ orun bí, kí ayé sì
Ẹ Fèyí Kọ́gbọ́n Mo délé Alárá N ò gbọ́ poroporo odó Mo délé Ajerò N ò gbọ́ kọ̀ǹkọ̀ṣọ̀ ajọ̀ Mo
Ó Di Pẹ́ Ǹ Túká Gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀ pé awọn ẹranko ló kọ́kọ́ dáyé ṣáájú àwa ènìyàn. Èyí