Ìṣẹ́ àti Òṣì — Núrénì Àrẹ̀mú Bakẹnnẹ
Gbogbo rògbòdìyàn tó ń lọ ní’gboro tojú sú ni pátápátá.Tí t’ arúgbó t’omidan fi ń sá hílà-híloTí ìbẹ̀rù ìṣẹ́ òhun […]
Gbogbo rògbòdìyàn tó ń lọ ní’gboro tojú sú ni pátápátá.Tí t’ arúgbó t’omidan fi ń sá hílà-híloTí ìbẹ̀rù ìṣẹ́ òhun […]
Àwọn ènìyàn ìlú mi ńlá àwọn ìka wọ̀bìà wọ́n mọ́níbi ẹ̀jẹ̀ tó ń tọ jádepẹ̀lú ìgbàgbé pé ìka àárínń padà
Adé-ìmọ́lẹ̀ náà wúwo lórí ẹni mímọ́ náà, Ó rúnjúpọ̀ fún àpọ̀jù-ìmọ́lẹ̀tó wọ̀ ọ́ lójú, ó ti kó ṣáwùjọ̀ aláìrọ́runwọ̀. a
Ìfarajìn Fún D Eléyìí le wá sópin ní àwọn ọ̀nà méjì Pẹ̀lú rẹ, Mo fẹ́ èyí tó dára –Níbi tó
Igúnnugún bà lórùléOjú kálé, Ojú káko. Òrí akéwì kò ní jábọ́ Kó má yí nǹkan. Kí láǹfààní orógbó? A pa
Ìtìjú Dà? Àyìndé dé tòhun tàròfọ̀ Orí Àyìndé ò ní balẹ̀ Kó má mà yí nǹkan. Ohun ojú akéwì ń
Ayé yìí ò le Pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ lejò ń gàgbọn. Ayé yìí ò gba gìrìgìrì Lọ̀gà fi ń tẹlẹ̀ jẹ́jẹ́jẹ́. Ẹ̀sọ̀ pẹ̀lẹ́
ẸFÚNṢETÁN Ọya ṣe tán ó rà sílé ‘rá Ṣàngó ṣe tán ó wọlẹ̀ní Kòso Ẹfún ṣe tán ó lójú orógbó
Nígbà mo wà lọ́mọ ọwọ́ Mo gbájú métè ìyáà mi korokoro Nígbà mo wà pẹ̀lú bàbá èmi Mo wòye ìsọ̀rọ̀sí
Ẹni tó bá mọ àlùmúńtù Ẹ bá mi wá a lọ, a ní gbólóhùn Ẹni tó bá mọ abà tí