Àwọn Ilé Aláwo – Rahma O. Jimoh
Àwọn ènìyàn ìlú mi ńlá àwọn ìka wọ̀bìà wọ́n mọ́níbi ẹ̀jẹ̀ tó ń tọ jádepẹ̀lú ìgbàgbé pé ìka àárínń padà […]
Àwọn ènìyàn ìlú mi ńlá àwọn ìka wọ̀bìà wọ́n mọ́níbi ẹ̀jẹ̀ tó ń tọ jádepẹ̀lú ìgbàgbé pé ìka àárínń padà […]
Adé-ìmọ́lẹ̀ náà wúwo lórí ẹni mímọ́ náà, Ó rúnjúpọ̀ fún àpọ̀jù-ìmọ́lẹ̀tó wọ̀ ọ́ lójú, ó ti kó ṣáwùjọ̀ aláìrọ́runwọ̀. a
Lati ọwọ́ọ Wálé Adébánwi, Akin Adéṣọ̀kàn, Tádé Ìpàdéọlá, Ebenezer Ọbádáre, àti Oyèníyì Òkúnoyè. Ni nǹkan bíi ọdún mẹ́fà sẹ́yìn ni
Tata Àti Ìrẹ̀: Ẹranko Olóhùn Tó Bá Ìgbà Mu / On The Grasshopper And Cricket Ewì inú Ayé ò kú
Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú / On Death Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú I. Ǹjẹ́ ikú le è jẹ́ orun bí, kí ayé sì
Ó Di Pẹ́ Ǹ Túká Gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀ pé awọn ẹranko ló kọ́kọ́ dáyé ṣáájú àwa ènìyàn. Èyí
Ìtan Arìnrìn-àjò kan/ The Child’s story Ìtan Arìnrìn-àjò kan Ní àkókò kan ṣẹ́yìn, ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún tí ó dára ṣẹ́yìn.
Ìjẹ́ Abiyamọ Ní Àríwá/ Being a mother in the north Ìjẹ́ abiyamọ ni àríwá Mo máa ń lo ìgbà mi
Àkọ́lé Ìwé: Ìgbà Èwe (Childhood)Ònkọ̀wé: Emily R. Grosholz Olùtúmọ̀ sí Èdè Yorùbá: Kọ́lá Túbọ̀sùnỌdún Tó Jáde: 2021Olùtẹ̀wé: Ouida BooksISBN: 978-978-990-701-4
Ọ̀nà tí ó yá jù láti dá’ná sun ara ẹni Ni nípa fifi iná sí ilé ẹni. Òlùkọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì