Ilé-Ogbó | Uthman Yusuf Abiodun
Ìtàn àròsọ yìí dálé ìtàn ìsẹ̀dálẹ̀ ìlú kan tí à ń pè ní ILÉ-OGBÓ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun, ILÉ-OGBÓ wà ní […]
Ìtàn àròsọ yìí dálé ìtàn ìsẹ̀dálẹ̀ ìlú kan tí à ń pè ní ILÉ-OGBÓ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun, ILÉ-OGBÓ wà ní […]
Ẹni tí yóò bá pẹ̀gàn àjànàkú ni yóò sọ pé òun rí nǹkan fìrí. Igi pọ̀ nígbó àmọ́ ọ̀tọ̀ ni
Ìlú Ìkìrun wà ní apá àríwá ìlà-oòrùn ti ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìkìrun wà láàrin látítúùdì 7 dìgìríì ẹsẹ̀
Àwọn ará Ẹ̀gbá tí ó tèdó sí ìpínlẹ̀ Ògùn lónìí jẹ́ ọ̀kan nínú ojúlówó ọmọ Yorùbá. A lè pín Ẹ̀gbá
ẸFÚNṢETÁN Ọya ṣe tán ó rà sílé ‘rá Ṣàngó ṣe tán ó wọlẹ̀ní Kòso Ẹfún ṣe tán ó lójú orógbó
Ìlú ńlá tí ó ní orúkọ, ipò, ẹnu àti ìgbóyà ni ìlú Ọ̀gbàgì-Àkókó jẹ́ láàrín gbogbo àwọn ìjo̩ba ìbílè̩ Àkókó
Òru là ń ṣèkà ẹni tó ṣe lọ́sàn-án kò fara rere lọ. Ilẹ̀ ti ta sí i ti àwọn ọmọ
Ó Di Pẹ́ Ǹ Túká Gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀ pé awọn ẹranko ló kọ́kọ́ dáyé ṣáájú àwa ènìyàn. Èyí
Òpóǹló ni mo wà tí mo ti máa ń gbọ́ nípa ìlú Èkó. Oríṣiríṣi ni atilẹ̀ máa ń gbọ́ ni