Àwọn ènìyàn ìlú mi ńlá àwọn ìka wọ̀bìà wọ́n mọ́níbi ẹ̀jẹ̀ tó ń tọ jádepẹ̀lú ìgbàgbé pé ìka àárínń padà tọ́ka sí wọ́n. À ń…
Adé-ìmọ́lẹ̀ náà wúwo lórí ẹni mímọ́ náà, Ó rúnjúpọ̀ fún àpọ̀jù-ìmọ́lẹ̀tó wọ̀ ọ́ lójú, ó ti kó ṣáwùjọ̀ aláìrọ́runwọ̀. a gbe dè sórí àpèré,Òrìṣà náà…
Ìfarajìn Fún D Eléyìí le wá sópin ní àwọn ọ̀nà méjì Pẹ̀lú rẹ, Mo fẹ́ èyí tó dára –Níbi tó jẹ́ pé a ti ń…
Igúnnugún bà lórùléOjú kálé, Ojú káko. Òrí akéwì kò ní jábọ́ Kó má yí nǹkan. Kí láǹfààní orógbó? A pa á, kò láwẹ́ A jẹ́,…
Nígbà kan rí, àwọn ẹranko kéréjekéréje bi Eèrà, Ìjàlọ, Eku, Aáyán, Ikán àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ yan Ìjàlọ kó máa ṣe olorí wọn. Wọ́n ṣe…
Lati ọwọ́ọ Wálé Adébánwi, Akin Adéṣọ̀kàn, Tádé Ìpàdéọlá, Ebenezer Ọbádáre, àti Oyèníyì Òkúnoyè. Ni nǹkan bíi ọdún mẹ́fà sẹ́yìn ni àwọn ònkọ̀wé yìí sowọ́pọ̀ kọ…
Ìtìjú Dà? Àyìndé dé tòhun tàròfọ̀ Orí Àyìndé ò ní balẹ̀ Kó má mà yí nǹkan. Ohun ojú akéwì ń rí gọntíọ Ó di dandan…
Ayé yìí ò le Pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ lejò ń gàgbọn. Ayé yìí ò gba gìrìgìrì Lọ̀gà fi ń tẹlẹ̀ jẹ́jẹ́jẹ́. Ẹ̀sọ̀ pẹ̀lẹ́ ló láyé Dúníyàn ò fẹ́…
Ìtàn àròsọ yìí dálé ìtàn ìsẹ̀dálẹ̀ ìlú kan tí à ń pè ní ILÉ-OGBÓ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun, ILÉ-OGBÓ wà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun ibẹ̀ náà sì…
Ẹ jógun ó mí, ẹ ṣìmẹ̀dọ̀ n’ìyáàlù ń ké. Àmọ́ ọ̀rọ Nìjéè só síni lẹ́nu, ó tún buyọ̀ si. Iyọ̀ àlàáfíà ò sé tu dànù…