Dẹ́rẹ́bà Yìí Rọra! | Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀
Ayé yìí ò le Pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ lejò ń gàgbọn. Ayé yìí ò gba gìrìgìrì Lọ̀gà fi ń tẹlẹ̀ jẹ́jẹ́jẹ́. Ẹ̀sọ̀ pẹ̀lẹ́ […]
Ayé yìí ò le Pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ lejò ń gàgbọn. Ayé yìí ò gba gìrìgìrì Lọ̀gà fi ń tẹlẹ̀ jẹ́jẹ́jẹ́. Ẹ̀sọ̀ pẹ̀lẹ́ […]
Ìtàn àròsọ yìí dálé ìtàn ìsẹ̀dálẹ̀ ìlú kan tí à ń pè ní ILÉ-OGBÓ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun, ILÉ-OGBÓ wà ní
Ẹ jógun ó mí, ẹ ṣìmẹ̀dọ̀ n’ìyáàlù ń ké. Àmọ́ ọ̀rọ Nìjéè só síni lẹ́nu, ó tún buyọ̀ si. Iyọ̀
Ẹni tí yóò bá pẹ̀gàn àjànàkú ni yóò sọ pé òun rí nǹkan fìrí. Igi pọ̀ nígbó àmọ́ ọ̀tọ̀ ni
Ìlú Ìkìrun wà ní apá àríwá ìlà-oòrùn ti ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìkìrun wà láàrin látítúùdì 7 dìgìríì ẹsẹ̀
Àwọn ará Ẹ̀gbá tí ó tèdó sí ìpínlẹ̀ Ògùn lónìí jẹ́ ọ̀kan nínú ojúlówó ọmọ Yorùbá. A lè pín Ẹ̀gbá
ẸFÚNṢETÁN Ọya ṣe tán ó rà sílé ‘rá Ṣàngó ṣe tán ó wọlẹ̀ní Kòso Ẹfún ṣe tán ó lójú orógbó
Odò SOGÍDÍ jẹ́ odò ìyanu tí ó wà ní ìlú kan lẹ́bà Ọ̀yọ́ Aláàfin, ìlú Áwẹ́ ní ìjọba ìbílẹ̀ Afijíó
Ìlú ńlá tí ó ní orúkọ, ipò, ẹnu àti ìgbóyà ni ìlú Ọ̀gbàgì-Àkókó jẹ́ láàrín gbogbo àwọn ìjo̩ba ìbílè̩ Àkókó