Ọ̀kànlélọ́gọ́ta Ọdún Nínú Ìyà | Mustapha Sherif
Àrà mí ò rírí, mo rórí Ológbò látẹ Ajá wẹ̀wù, ó rósọ, ó tún gbọ́mọ́ dáni Èké dáyé, áásà dàpòmú […]
Àrà mí ò rírí, mo rórí Ológbò látẹ Ajá wẹ̀wù, ó rósọ, ó tún gbọ́mọ́ dáni Èké dáyé, áásà dàpòmú […]
A fẹ́ á jẹ máà fẹ́ á yó, Tó ń fúnni lóko ìdí ọ̀pẹ ro. Mo gbédìí fórílẹ̀-èdè, Tó sọ̀yà
Àkọ́lé Ìwé: Ìgbà Èwe (Childhood)Ònkọ̀wé: Emily R. Grosholz Olùtúmọ̀ sí Èdè Yorùbá: Kọ́lá Túbọ̀sùnỌdún Tó Jáde: 2021Olùtẹ̀wé: Ouida BooksISBN: 978-978-990-701-4
Ìlẹ̀kẹ̀ má jà á sílé má jà á síta ibì kan ni yóò já sí lọ́jọ́ kan. Dùnúnkẹ́ rẹwà lọmọ.
Olú ti d’ẹ́nu ní ìbúǹbú Ó di dandan kó jẹun. Ebi kìí wọnú kọ́rọ̀ míì ó wọ̀ ọ́ Òrìṣà bí ọ̀fun ò sí
ỌMỌ ÒRUKÀN Ikọ́ wíwú ológìnní kìí ṣàfiṣe Ìran baba wọn níí wúkọ́ fee. Gbígbó ajá kì í kúkú pajá. Ìran
Ẹ̀rù àwọn ará ibí bà mí jọjọ. Ẹrù àìbìkítà wọn a máa ṣe mí bí ọyẹ́ ti ń ṣe ọmọ
Ṣóo wo iwájú tóò r’ẹ́nìkan O w’ẹ̀yìn wò, óò r’éèyàn L’ọ́tùn-ún l’ósì, ilẹ̀ tẹ́ lọ bẹẹrẹ Àṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, o ní
Òpóǹló ni mo wà tí mo ti máa ń gbọ́ nípa ìlú Èkó. Oríṣiríṣi ni atilẹ̀ máa ń gbọ́ ni