Òtítọ́ Lérè | Ọláyàtọ̀ Ọláolúwa
Ní ìlú kan tí à ń pè ní Bíkú, Bí-ikú-ilé-ò-pa-ni ni àjápè orúkọ ìlú yìí ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn fẹ́ràn […]
Ní ìlú kan tí à ń pè ní Bíkú, Bí-ikú-ilé-ò-pa-ni ni àjápè orúkọ ìlú yìí ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn fẹ́ràn […]
Àyàjọ́ Falẹ! À ń gbòròmọdiẹ lọ́wọ́ ikú Tonídìí ní í dà nígbẹ̀yìn bídìí bàjẹ́ Ó tún ti ṣẹ̀ bó ti
Ìwé Le! Túlẹ̀, ẹ sáré wá Akẹ́kọ̀ọ́, ẹ wá gbọ́ nàsíà Òkun kì í hó ruru Ká wà á ruru,
Agbẹ́kẹ̀lé Ènìyàn Mo gbọ́ pé ayé wà Mo múra èrò ìjìnlẹ̀ Mo rí i pẹ́dàá ń ráyé lò Mo múra,
Okùn Ìfẹ́ Yi! Ìfẹ́ pọ́gbọ̀n, ó jọgbọ̀n Ìfẹ̀ pégba, ó jugba Ìfẹ́ pérínwó, ó jurínwó Ìfẹ́ẹ̀fẹ́ táyé fẹ́lá lóko Kò
ỌJÀ LAYÉ ỌJÀ LAYÉ Ọjà layé ọ̀rẹ́ mìi, Ọjà layé ará. Gbogbo ọmọ adáríhunrun pátá lówá nájà láyé, Dandan sì
Ọdún Ọlọ́jọ́ jẹ́ ọdún tó wuyì tó sì ṣe pàtàkì ní ilé-ifẹ̀, ọdọọdún ni wọ́n máa ń ṣe ọdún yìí.
Mi ò rántí ìgbà tí mo kọ́kọ́ gbọ́ gbólóhùn “Ọlọ́jọ́” nínú ọ̀rọ̀, àmọ́ mo rántí wípé nígbà èwe mi, tí
Ìjẹ́ Abiyamọ Ní Àríwá/ Being a mother in the north Ìjẹ́ abiyamọ ni àríwá Mo máa ń lo ìgbà mi
Èèmọ̀ Ní Pópó Ẹ wá wo ohun tí mo rí Ẹ dákun ẹ wá Ṣẹ̀ídà. Kàyéfì lohun tí mo rí