Òru là ń ṣèkà ẹni tó ṣe lọ́sàn-án kò fara rere lọ. Ilẹ̀ ti ta sí i ti àwọn ọmọ wòlìbísà tí ń ja àwọn…
Nígbà mo wà lọ́mọ ọwọ́ Mo gbájú métè ìyáà mi korokoro Nígbà mo wà pẹ̀lú bàbá èmi Mo wòye ìsọ̀rọ̀sí rẹ̀ Mo wẹnu àwọn tí…
Láyíwọlá ò sẹ̀sẹ̀ máa f’ẹ́wọ́. Ògbóntarìgì olè ni. Kìí ṣe ọlọ́sà rárá o. Tó bá ti kọjáa àfọwọ́rá, kìí bá wọn gbèro rẹ̀. Fún Láyíwọlá…
Ẹni tó bá mọ àlùmúńtù Ẹ bá mi wá a lọ, a ní gbólóhùn Ẹni tó bá mọ abà tí ikú ń gbé Ẹ bá…
Ìlú kan gógó, Ilu òf'ara rọ Àwọn ará ìlú gaan ò rẹ́ẹ̀rín. Àṣe k'árówóná òdàbí k'álówó nílé k'álówó nílé gan-an òdàbí k’álówó lápò k’álówó lápò…
Ìdùnnú a ṣubú lu ayọ̀ Lọ́jọ́ a bá bímọ tuntun sáyé Tẹbítará a kí túńfúlù káàbọ̀. Bọ́jọ́ ṣe ń gorí ọjọ́ Tóṣù ń gorí oṣù…
Èyí jẹ́ ọ̀rọ̀ tí àwọn olùdásílẹ́ Àtẹ́lẹwọ́, Rasaq Malik àti Ibrahim Ọ̀rẹ́dọlá kà ní ibi ìpèjọ àwọn oníròyìn láti ṣe ayẹyẹ ọdún karùn-ún tí wọ́n…
Dèbórà, Obìnrin Ogun Ìmísí: Ìwé nípa ìgbésí ayé Àyìnlá Ọmọ Wúrà Ìwé tó kọ nípa a rẹ̀ kìí ṣé mímọ́ Bíkòṣe ti mímọ̀— Ìmọ̀ ogun.…
Káràkátà Mo ya àwòrán yìí ní ọdún 2020 nígbàtí àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 gbòde kan. Ìyàlẹ́nu ló jẹ fún mí nígbà tí mo ri ọ̀pọ̀ ènìyàn…
Ta Ni Kí Ń Bi? Mo wò òréré ayé yíká Ayé ò yé mí rárá Mo wò sánmọ̀ lọ súà Kò yé mi bó ṣe…