Àlàmú Olókùn | Ọláyàtọ̀ Ọláolúwa
Àlàmú Olókùn Ọ̀kan lára awọn ẹranko tí ó kéré jùlọ ni Aláǹtakùn (a-lá-rìn-ta-okùn-mọ́lẹ̀), bí ó bá ń rìn, yóò máa […]
Àlàmú Olókùn Ọ̀kan lára awọn ẹranko tí ó kéré jùlọ ni Aláǹtakùn (a-lá-rìn-ta-okùn-mọ́lẹ̀), bí ó bá ń rìn, yóò máa […]
Ní ìlú kan tí à ń pè ní Bíkú, Bí-ikú-ilé-ò-pa-ni ni àjápè orúkọ ìlú yìí ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn fẹ́ràn
Ọdún Ọlọ́jọ́ jẹ́ ọdún tó wuyì tó sì ṣe pàtàkì ní ilé-ifẹ̀, ọdọọdún ni wọ́n máa ń ṣe ọdún yìí.
Mi ò rántí ìgbà tí mo kọ́kọ́ gbọ́ gbólóhùn “Ọlọ́jọ́” nínú ọ̀rọ̀, àmọ́ mo rántí wípé nígbà èwe mi, tí
Bí aré kò bá tó aré a kì í pòwe, bí ọ̀rọ̀ kò bá tọ́rọ̀ a kìí fìtàn balẹ̀, bí
Kò sí ẹnì kankan tí kò mọ Ìyá àgbà ní abàá Alẹ́mọ́, kìí sọ ìtàn kan ní ẹ̀ẹ̀mejì. Àgbà òpìtàn
Ìlẹ̀kẹ̀ má jà á sílé má jà á síta ibì kan ni yóò já sí lọ́jọ́ kan. Dùnúnkẹ́ rẹwà lọmọ.
À ṣé àwọn tí wọn ń pé Àlàmú l’Ájá kò sọ àsọrégè rárá. Bí ó tí lẹ̀ jẹ́ pé àbísọ
Ìbínú kò mọ̀ pé olówó òun ò lẹ́sẹ̀ ńlẹ̀. Ọ̀rẹ́ wa kan ló fi àṣejù kó bá ara rẹ̀ lẹ́nu
Àgbẹ̀ paraku ni Àkànó. Ìṣẹ́ àgbẹ̀ yí náà ni ó ń ṣe tí ó fi fẹ́ ìyàwó mérin tí ó