Kọ́kọ́rọ́ Ilé |Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀
Ọjọ́ tí mo ti ń fi àwo òyìnbó jẹun kò fọ́ mọ́ mi lọ́wọ́ rí. Ohun tí ènìyàn kúkú […]
Ọjọ́ tí mo ti ń fi àwo òyìnbó jẹun kò fọ́ mọ́ mi lọ́wọ́ rí. Ohun tí ènìyàn kúkú […]
Inú títa ló jí mi. Mo tilẹ̀ kọ́kọ́ rò pé àlá tí mo lá ni ó fà á ni –
Ọmọ bíbí ìlú Ifón ni Abíọ́dún; ó sì fẹ́ràn ìlú rẹ̀ púpọ̀. Ọkàn ò jọ̀kan ẹ̀bùn ni Olódùmarè fi jíǹkí
Apá Kiní Emọ́ kú ojú òpó dí Eésùn là, o là dànù Ọ̀pálánbá ọtí èèbó fọ́ Onígbá sọọ́ kò ri
Kíkorò Ewúro Gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Adùn ló yẹ kí ó gbẹ̀yìn ewúro Ṣùgbọ́n kò sẹ́ni tí ó ń
Akéwì Èmi lakéwì, mo lóyin létè. Mo kẹ̀tẹ̀ǹfẹ̀ ìmọ̀ Mo le sọrọ́ dòótọ́ bí n bá fẹ́! Bó wù mí,
Bàbá afọ́jú kan wà tí ó máa ń kọjá níwájú ilé wa nígbà tí mo wà ní kékeré. Ó dúdú
Ẹ forí jìn mí o, ẹ̀yin tí è ń gbé inú ilé yí. Ẹ̀rù ajá yín tí ó ń bà
Bí mo ṣe gbọ́ ìbéérè tí Dádì béèrè lọ́wọ́ mi, ṣe ni mo fi ẹ̀rín tó fẹ́ wú jáde lẹ́nu
MÀÁMI Ọ̀WỌ́N Màámi ọ̀wọ́n, Ìdùnú àti àyọ̀ ni mo fi kọ ìwé yìí. Báwo ni ǹkàn? Gbogbo ilé ńkọ́? Ṣe