Ọ̀rọ̀ Olóòtú: Ìtọ́wò Àkójọpọ̀ Àtẹ́lẹwọ́
Nínú ọ̀rọ̀ ìṣáájú fún ìwé ‘Adéjọké ará Ìjílèje—Àkójọpọ̀ ìtàn kéékèèké Adébáyọ Fálétí,’ Òjọgbọ́n Ọlátúndé O. Ọlátúnjí kọ wípé: “Àwọn ọmọdé […]
Nínú ọ̀rọ̀ ìṣáájú fún ìwé ‘Adéjọké ará Ìjílèje—Àkójọpọ̀ ìtàn kéékèèké Adébáyọ Fálétí,’ Òjọgbọ́n Ọlátúndé O. Ọlátúnjí kọ wípé: “Àwọn ọmọdé […]
A dúpẹ́ fún àwọn ohun tí ẹ fi ṣowọ́ sí wa fun àtẹ̀jade Kínní. Àtẹ̀jade kejì yíò jẹ́ ìfisorí fún
Bàbá afọ́jú kan wà tí ó máa ń kọjá níwájú ilé wa nígbà tí mo wà ní kékeré. Ó dúdú
Ẹ forí jìn mí o, ẹ̀yin tí è ń gbé inú ilé yí. Ẹ̀rù ajá yín tí ó ń bà
Moti dé’lé ayé ọjọ́ ti pẹ́, Moti d’ókè eèpẹ̀ ọ̀nà ti jì, Ṣebí ojúlarí ọ̀rẹ́ ò dénú. Ṣààsà ènìyàn ní
Gbogbo ohun tí a bá ṣe lónìí, ọ̀rọ̀ ìtàn ni bó dọ̀la Gbogbo ayé ló máa tán Gbogbo wa la