Àtẹ́lẹwọ́

Ìwé ìròyìn náà

Àkójọpọ̀ àwọn lẹ́tà Yorùbá tí ó wà láàyè.

A máa ń tẹ̀ ẹ́ jáde ní ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀. Ka ní àkókò tó bá ọ lára ​​mu.

Ẹni tó bá mọ àlùmúńtù Ẹ bá mi wá a lọ, a ní gbólóhùn Ẹni tó bá mọ abà tí […]

Ìlú kan gógó, Ilu òf'ara rọ Àwọn ará ìlú gaan ò rẹ́ẹ̀rín. Àṣe k'árówóná òdàbí k'álówó nílé k'álówó nílé gan-an […]

Ẹ kú u dédé àsìkò yìí o ẹ̀yin òǹkàwé wa, a sì kú ọdún tuntun. Ọdún ayọ̀ ni yóò jẹ́ […]

Oore Ló Pé Oore ló pé Ẹ jẹ́ á ṣoore Ìkà ò pé Gbogbo Mùtúnmùwà! Bó o bá ṣe é […]

Tata Àti Ìrẹ̀: Ẹranko Olóhùn Tó Bá Ìgbà Mu / On The Grasshopper And Cricket Ewì inú Ayé ò kú […]

Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú / On Death Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú I. Ǹjẹ́ ikú le è jẹ́ orun bí, kí ayé sì […]

Ẹ Fèyí Kọ́gbọ́n Mo délé Alárá N ò gbọ́ poroporo odó Mo délé Ajerò N ò gbọ́ kọ̀ǹkọ̀ṣọ̀ ajọ̀ Mo […]

Ó Di Pẹ́ Ǹ Túká Gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀ pé awọn ẹranko ló kọ́kọ́ dáyé ṣáájú àwa ènìyàn. Èyí […]

Àlàmú Olókùn Ọ̀kan lára awọn ẹranko tí ó kéré jùlọ ni Aláǹtakùn (a-lá-rìn-ta-okùn-mọ́lẹ̀), bí ó bá ń rìn, yóò máa […]

Ẹ̀yin Ònkàwé, Ẹ kú u dédé àsìkò yìí o ẹ̀yin òǹkàwé wa, a sì kú ìpalẹ̀mọ́ pọ̀pọ̀ṣìnṣìn odún tuntun tó […]

Ìtan Arìnrìn-àjò kan/ The Child’s story Ìtan Arìnrìn-àjò kan Ní àkókò kan ṣẹ́yìn, ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún tí ó dára ṣẹ́yìn. […]

    Ní ìlú kan tí à ń pè ní Bíkú,  Bí-ikú-ilé-ò-pa-ni ni àjápè orúkọ ìlú yìí ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn fẹ́ràn […]