Àtẹ́lẹwọ́

Ìwé ìròyìn náà

Àkójọpọ̀ àwọn lẹ́tà Yorùbá tí ó wà láàyè.

A máa ń tẹ̀ ẹ́ jáde ní ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀. Ka ní àkókò tó bá ọ lára ​​mu.

Ẹ jógun ó mí, ẹ ṣìmẹ̀dọ̀ n’ìyáàlù ń ké. Àmọ́ ọ̀rọ Nìjéè só síni lẹ́nu, ó tún buyọ̀ si. Iyọ̀ […]

Ẹni tí yóò bá pẹ̀gàn àjànàkú ni yóò sọ pé òun rí nǹkan fìrí. Igi pọ̀ nígbó àmọ́ ọ̀tọ̀ ni […]

Báwo ni a ṣe fẹ́ pe káńbó tí a kò nì í júbà imú. Báwo ni a ṣe fẹ́ pe […]

Ìlú Ìkìrun wà ní apá àríwá ìlà-oòrùn ti ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìkìrun wà láàrin látítúùdì 7 dìgìríì ẹsẹ̀ […]

Àwọn ará Ẹ̀gbá tí ó tèdó sí ìpínlẹ̀ Ògùn lónìí jẹ́ ọ̀kan nínú ojúlówó ọmọ Yorùbá. A lè pín Ẹ̀gbá […]

ẸFÚNṢETÁN Ọya ṣe tán ó rà sílé 'rá Ṣàngó ṣe tán ó wọlẹ̀ní Kòso Ẹfún ṣe tán ó lójú orógbó […]

Odò SOGÍDÍ jẹ́ odò ìyanu tí ó wà ní ìlú kan lẹ́bà Ọ̀yọ́ Aláàfin, ìlú Áwẹ́ ní ìjọba ìbílẹ̀ Afijíó […]

Ìlú ńlá tí ó ní orúkọ, ipò, ẹnu àti ìgbóyà ni ìlú Ọ̀gbàgì-Àkókó jẹ́ láàrín gbogbo àwọn ìjo̩ba ìbílè̩ Àkókó […]

Orúkọ mi ni Kọ́lá Túbọ̀sún. Mo wá láti ibi kan tí a ǹpé ní Ibàdàn, níbè ni wón bí mi […]

Òru là ń ṣèkà ẹni tó ṣe lọ́sàn-án kò fara rere lọ. Ilẹ̀ ti ta sí i ti àwọn ọmọ […]

Nígbà mo wà lọ́mọ ọwọ́ Mo gbájú métè ìyáà mi korokoro Nígbà mo wà pẹ̀lú bàbá èmi Mo wòye ìsọ̀rọ̀sí […]

Láyíwọlá ò sẹ̀sẹ̀ máa f’ẹ́wọ́. Ògbóntarìgì olè ni. Kìí ṣe ọlọ́sà rárá o. Tó bá ti kọjáa àfọwọ́rá, kìí bá […]