Ìwé ìròyìn náà
Àkójọpọ̀ àwọn lẹ́tà Yorùbá tí ó wà láàyè.
A máa ń tẹ̀ ẹ́ jáde ní ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀. Ka ní àkókò tó bá ọ lára mu.
Àrà mí ò rírí, mo rórí Ológbò látẹ Ajá wẹ̀wù, ó rósọ, ó tún gbọ́mọ́ dáni Èké dáyé, áásà dàpòmú […]
A fẹ́ á jẹ máà fẹ́ á yó, Tó ń fúnni lóko ìdí ọ̀pẹ ro. Mo gbédìí fórílẹ̀-èdè, Tó sọ̀yà […]
Àkọ́lé Ìwé: Ìgbà Èwe (Childhood)Ònkọ̀wé: Emily R. Grosholz Olùtúmọ̀ sí Èdè Yorùbá: Kọ́lá Túbọ̀sùnỌdún Tó Jáde: 2021Olùtẹ̀wé: Ouida BooksISBN: 978-978-990-701-4 […]
Káràkátà Mo ya àwòrán yìí ní ọdún 2020 nígbàtí àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 gbòde kan. Ìyàlẹ́nu ló jẹ fún mí nígbà […]
Ta Ni Kí Ń Bi? Mo wò òréré ayé yíká Ayé ò yé mí rárá Mo wò sánmọ̀ lọ súà […]
Bí aré kò bá tó aré a kì í pòwe, bí ọ̀rọ̀ kò bá tọ́rọ̀ a kìí fìtàn balẹ̀, bí […]
Kò sí ẹnì kankan tí kò mọ Ìyá àgbà ní abàá Alẹ́mọ́, kìí sọ ìtàn kan ní ẹ̀ẹ̀mejì. Àgbà òpìtàn […]
Ọ̀nà tí ó yá jù láti dá'ná sun ara ẹni Ni nípa fifi iná sí ilé ẹni. Òlùkọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì […]
Ìlẹ̀kẹ̀ má jà á sílé má jà á síta ibì kan ni yóò já sí lọ́jọ́ kan. Dùnúnkẹ́ rẹwà lọmọ. […]
Olú ti d'ẹ́nu ní ìbúǹbú Ó di dandan kó jẹun. Ebi kìí wọnú kọ́rọ̀ míì ó wọ̀ ọ́ Òrìṣà bí ọ̀fun ò sí […]
Olóko ń sun kún Oní igba ewùrà ló nù ní ódẹ̀ òhun Ará ilé mi ní: òhun ò l'oko, bẹ́ẹ̀ […]
À ṣé àwọn tí wọn ń pé Àlàmú l’Ájá kò sọ àsọrégè rárá. Bí ó tí lẹ̀ jẹ́ pé àbísọ […]