Láwuyì Ògúnníran: Àjànàkú sùn bí òkè!
Eerin wó, Àjànàkú sùn bí òkè! O ṣe ni láàánú gidigidi láti gbọ́ pé Bàbá Láwuyì Ògúnníran, ọ̀kan gbòógí nínú […]
Eerin wó, Àjànàkú sùn bí òkè! O ṣe ni láàánú gidigidi láti gbọ́ pé Bàbá Láwuyì Ògúnníran, ọ̀kan gbòógí nínú […]
Àgbẹ̀ paraku ni Àkànó. Ìṣẹ́ àgbẹ̀ yí náà ni ó ń ṣe tí ó fi fẹ́ ìyàwó mérin tí ó
Ọjọ́ tí mo ti ń fi àwo òyìnbó jẹun kò fọ́ mọ́ mi lọ́wọ́ rí. Ohun tí ènìyàn kúkú
Inú títa ló jí mi. Mo tilẹ̀ kọ́kọ́ rò pé àlá tí mo lá ni ó fà á ni –
Kò sẹ́ranko bí kìnnìún níjù. Bó dolókìtì ẹni tí ó ṣe bí ọ̀bọ ò sí. Ẹranko tí ó sọ pé
Ẹnìkan Ò Layé Ẹni ayé ńṣe maràba fún ó sọ́ra fẹ́nu aráyé Ẹ wí fún gbogbo molegòkè-molesọ̀ pé mo ní
Ọmọ mí Mo bá wọn ná’jà Akẹ̀ẹ̀sán Mo bá wọn pé lọ́jà Orísúnbáre Ohun mò ń wá di tíntín abẹ́rẹ́
Mo lé téńté sórí igi odán mobojú wolẹ̀ láti wo àwọn ẹ̀dá tí Elédùmarè dá sílé Ayé À’teku, à’teye, àti
Ọmọ bíbí ìlú Ifón ni Abíọ́dún; ó sì fẹ́ràn ìlú rẹ̀ púpọ̀. Ọkàn ò jọ̀kan ẹ̀bùn ni Olódùmarè fi jíǹkí
Coro ló pojú kòró jẹ Ṣebí láti ọjọ́ táláyé ti dáyé L’ayé tí ń yí, tí ọmọ adáríhunrun ti ń