Wèrè Alásọ àti Àwọn Ewì Míràn |Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀
Ta Ni Kí Ń Bi? Mo wò òréré ayé yíká Ayé ò yé mí rárá Mo wò sánmọ̀ lọ súà […]
Ta Ni Kí Ń Bi? Mo wò òréré ayé yíká Ayé ò yé mí rárá Mo wò sánmọ̀ lọ súà […]
Bí aré kò bá tó aré a kì í pòwe, bí ọ̀rọ̀ kò bá tọ́rọ̀ a kìí fìtàn balẹ̀, bí
Ọ̀nà tí ó yá jù láti dá’ná sun ara ẹni Ni nípa fifi iná sí ilé ẹni. Òlùkọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì
Ìlẹ̀kẹ̀ má jà á sílé má jà á síta ibì kan ni yóò já sí lọ́jọ́ kan. Dùnúnkẹ́ rẹwà lọmọ.
Olú ti d’ẹ́nu ní ìbúǹbú Ó di dandan kó jẹun. Ebi kìí wọnú kọ́rọ̀ míì ó wọ̀ ọ́ Òrìṣà bí ọ̀fun ò sí
Olóko ń sun kún Oní igba ewùrà ló nù ní ódẹ̀ òhun Ará ilé mi ní: òhun ò l’oko, bẹ́ẹ̀
ÀTẸ́LẸWỌ́ did this project to celebrate Bàbá Láwuyì Ògúnníran, the famous author of Eégún Aláré and many other Yorùbá literature
Àgbà ọ̀pàpà paradà owó ará ìlú paradà ó dọbẹ̀ níkùn àgbà àgbà òṣèlú, àgbà ọ̀jẹ̀lú wọn jẹ̀lú jẹ̀lú, ìlú wó
Jòjòló akéwì tún dé Mo fẹ́ kọrin ewì sétí aráyé Ẹ yá mi létí yín. Ọ̀rọ̀ fẹ́ máa jábọ́ bí
Ìbínú kò mọ̀ pé olówó òun ò lẹ́sẹ̀ ńlẹ̀. Ọ̀rẹ́ wa kan ló fi àṣejù kó bá ara rẹ̀ lẹ́nu