Àlàmú Olókùn | Ọláyàtọ̀ Ọláolúwa
Àlàmú Olókùn Ọ̀kan lára awọn ẹranko tí ó kéré jùlọ ni Aláǹtakùn (a-lá-rìn-ta-okùn-mọ́lẹ̀), bí ó bá ń rìn, yóò máa […]
Àlàmú Olókùn Ọ̀kan lára awọn ẹranko tí ó kéré jùlọ ni Aláǹtakùn (a-lá-rìn-ta-okùn-mọ́lẹ̀), bí ó bá ń rìn, yóò máa […]
Ẹ̀yin Ònkàwé, Ẹ kú u dédé àsìkò yìí o ẹ̀yin òǹkàwé wa, a sì kú ìpalẹ̀mọ́ pọ̀pọ̀ṣìnṣìn odún tuntun tó
Mi ò rántí ìgbà tí mo kọ́kọ́ gbọ́ gbólóhùn “Ọlọ́jọ́” nínú ọ̀rọ̀, àmọ́ mo rántí wípé nígbà èwe mi, tí
Èyí jẹ́ ọ̀rọ̀ tí àwọn olùdásílẹ́ Àtẹ́lẹwọ́, Rasaq Malik àti Ibrahim Ọ̀rẹ́dọlá kà ní ibi ìpèjọ àwọn oníròyìn láti ṣe
Dèbórà, Obìnrin Ogun Ìmísí: Ìwé nípa ìgbésí ayé Àyìnlá Ọmọ Wúrà Ìwé tó kọ nípa a rẹ̀ kìí ṣé mímọ́
Èèmọ̀ Ní Pópó Ẹ wá wo ohun tí mo rí Ẹ dákun ẹ wá Ṣẹ̀ídà. Kàyéfì lohun tí mo rí
Àrà mí ò rírí, mo rórí Ológbò látẹ Ajá wẹ̀wù, ó rósọ, ó tún gbọ́mọ́ dáni Èké dáyé, áásà dàpòmú
A fẹ́ á jẹ máà fẹ́ á yó, Tó ń fúnni lóko ìdí ọ̀pẹ ro. Mo gbédìí fórílẹ̀-èdè, Tó sọ̀yà
Àkọ́lé Ìwé: Ìgbà Èwe (Childhood)Ònkọ̀wé: Emily R. Grosholz Olùtúmọ̀ sí Èdè Yorùbá: Kọ́lá Túbọ̀sùnỌdún Tó Jáde: 2021Olùtẹ̀wé: Ouida BooksISBN: 978-978-990-701-4
Káràkátà Mo ya àwòrán yìí ní ọdún 2020 nígbàtí àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 gbòde kan. Ìyàlẹ́nu ló jẹ fún mí nígbà