Ewì ní ìrántí Adébáyọ̀ Fálétí, Akínwùmí Ìṣọ̀lá, àti Ọládẹ̀jọ Òkédìjí |Kọ́dáolú Tolúlọpẹ́
Apá Kiní Emọ́ kú ojú òpó dí Eésùn là, o là dànù Ọ̀pálánbá ọtí èèbó fọ́ Onígbá sọọ́ kò ri […]
Apá Kiní Emọ́ kú ojú òpó dí Eésùn là, o là dànù Ọ̀pálánbá ọtí èèbó fọ́ Onígbá sọọ́ kò ri […]
À-pè-kánukò Àpèkánukò! Àpèṣ’ẹnu ṣùùtì Bí-i músù ú rẹ́ja nínú ike. Owó ní í jẹ́bẹ̀, ìwọ ọ̀rẹ́, Bí kò bá sí
Kíkorò Ewúro Gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Adùn ló yẹ kí ó gbẹ̀yìn ewúro Ṣùgbọ́n kò sẹ́ni tí ó ń
Nínú ọ̀rọ̀ ìṣáájú fún ìwé ‘Adéjọké ará Ìjílèje—Àkójọpọ̀ ìtàn kéékèèké Adébáyọ Fálétí,’ Òjọgbọ́n Ọlátúndé O. Ọlátúnjí kọ wípé: “Àwọn ọmọdé
A dúpẹ́ fún àwọn ohun tí ẹ fi ṣowọ́ sí wa fun àtẹ̀jade Kínní. Àtẹ̀jade kejì yíò jẹ́ ìfisorí fún
Ní ojoojúmọ́ ayé mi ni mo máá ń ronú nípa ayé àwa ẹ̀dá, nípa àditú ayé tí ó ń fi
Ṣèbí oun tí mo mọ̀n tí wọ́n má ń sọ ni pé òkùnkùn kìí bórí ìmọ́lẹ̀, pé irọ́ kìí jáwé
Ìwọ̀n ẹni là á mọ̀, A kì í mọ tẹni ẹlẹ́ni. Bí a ò bá ronú àti bùkèlè, Ó ṣe
Wón ní, Ikú ogun ló ń pa akíkanjú Ikú odò lo ń p’òmùwẹ̀ Ikú ẹwà ni wón ní ó ń
Ó kúkú ti pẹ́ tí Náírà ti ń gbọ́ nípa Kọ́bọ̀. Kódà ìtàn sọ fun u pé gẹ́lẹ́ tí Náírà