Ẹ jógun ó mí, ẹ ṣìmẹ̀dọ̀ n’ìyáàlù ń ké. Àmọ́ ọ̀rọ Nìjéè só síni lẹ́nu, ó tún buyọ̀ si. Iyọ̀ àlàáfíà ò sé tu dànù…
Ẹni tí yóò bá pẹ̀gàn àjànàkú ni yóò sọ pé òun rí nǹkan fìrí. Igi pọ̀ nígbó àmọ́ ọ̀tọ̀ ni igi ọ̀mọ̀. Kòkòrò pégba nígbó…
Báwo ni a ṣe fẹ́ pe káńbó tí a kò nì í júbà imú. Báwo ni a ṣe fẹ́ pe orí olóólà tí a kò…
Ìlú Ìkìrun wà ní apá àríwá ìlà-oòrùn ti ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ìkìrun wà láàrin látítúùdì 7 dìgìríì ẹsẹ̀ 50, àríwá ti ìlà agbede-ayé…
Àwọn ará Ẹ̀gbá tí ó tèdó sí ìpínlẹ̀ Ògùn lónìí jẹ́ ọ̀kan nínú ojúlówó ọmọ Yorùbá. A lè pín Ẹ̀gbá sí ònà mẹ́rin Aké ,…
ẸFÚNṢETÁN Ọya ṣe tán ó rà sílé 'rá Ṣàngó ṣe tán ó wọlẹ̀ní Kòso Ẹfún ṣe tán ó lójú orógbó Ẹfun ṣe tán ó wẹwù…
Odò SOGÍDÍ jẹ́ odò ìyanu tí ó wà ní ìlú kan lẹ́bà Ọ̀yọ́ Aláàfin, ìlú Áwẹ́ ní ìjọba ìbílẹ̀ Afijíó .Kòsí ìwádìí kankan tó fi…
Ìlú ńlá tí ó ní orúkọ, ipò, ẹnu àti ìgbóyà ni ìlú Ọ̀gbàgì-Àkókó jẹ́ láàrín gbogbo àwọn ìjo̩ba ìbílè̩ Àkókó mẹ́rẹ̀ẹ̀rin. Ìlú yìí ní agbára…
Orúkọ mi ni Kọ́lá Túbọ̀sún. Mo wá láti ibi kan tí a ǹpé ní Ibàdàn, níbè ni wón bí mi sí, àmọ́ ìlú Èkó ni…
Ẹ kú u dédé àsìkò yìí o ẹ̀yin òǹkàwé wa, a sì kú ọdún tuntun. Ọdún ayọ̀ ni yóò jẹ́ fún wa, ọ̀pọ̀ ọdún la…