Àbíkú | Sùmọ́nù Ajíbọ́lá Adéjùmọ̀
Aáyan ògbufọ̀ iṣẹ́ “Àbíkú” láti ọwọ́ Wọlé Ṣóyínká Asán, òfúútù fẹ́ẹ̀tẹ̀, aásà tí kò ní kán-ún ni gbogbo ìlẹ̀kẹ̀ tí […]
Aáyan ògbufọ̀ iṣẹ́ “Àbíkú” láti ọwọ́ Wọlé Ṣóyínká Asán, òfúútù fẹ́ẹ̀tẹ̀, aásà tí kò ní kán-ún ni gbogbo ìlẹ̀kẹ̀ tí […]
Inú títa ló jí mi. Mo tilẹ̀ kọ́kọ́ rò pé àlá tí mo lá ni ó fà á ni –
Kò sẹ́ranko bí kìnnìún níjù. Bó dolókìtì ẹni tí ó ṣe bí ọ̀bọ ò sí. Ẹranko tí ó sọ pé
Ọmọ mí Mo bá wọn ná’jà Akẹ̀ẹ̀sán Mo bá wọn pé lọ́jà Orísúnbáre Ohun mò ń wá di tíntín abẹ́rẹ́
Mo lé téńté sórí igi odán mobojú wolẹ̀ láti wo àwọn ẹ̀dá tí Elédùmarè dá sílé Ayé À’teku, à’teye, àti
Ẹ Bọ̀wọ̀ F’ágbà “Ajá tó r’ólówó ẹ̀ rojú, kín ní ó f’ólówó è se kò tié yé mi.” —Éégunmọgají Àyìnlá
Ọmọ bíbí ìlú Ifón ni Abíọ́dún; ó sì fẹ́ràn ìlú rẹ̀ púpọ̀. Ọkàn ò jọ̀kan ẹ̀bùn ni Olódùmarè fi jíǹkí
Coro ló pojú kòró jẹ Ṣebí láti ọjọ́ táláyé ti dáyé L’ayé tí ń yí, tí ọmọ adáríhunrun ti ń
Apá Kiní Emọ́ kú ojú òpó dí Eésùn là, o là dànù Ọ̀pálánbá ọtí èèbó fọ́ Onígbá sọọ́ kò ri
Egbìrìn ọ̀tẹ̀ bí à ń ṣé pa ìkan ni ọ̀kan rú ní ìlú mi. Ní àgbàlá òdòdó yìí ẹ̀gún ń