Lati ọwọ́ọ Wálé Adébánwi, Akin Adéṣọ̀kàn, Tádé Ìpàdéọlá, Ebenezer Ọbádáre, àti Oyèníyì Òkúnoyè. Ni nǹkan bíi ọdún mẹ́fà sẹ́yìn ni àwọn ònkọ̀wé yìí sowọ́pọ̀ kọ…
Ìlú kan gógó, Ilu òf'ara rọ Àwọn ará ìlú gaan ò rẹ́ẹ̀rín. Àṣe k'árówóná òdàbí k'álówó nílé k'álówó nílé gan-an òdàbí k’álówó lápò k’álówó lápò…
Oore Ló Pé Oore ló pé Ẹ jẹ́ á ṣoore Ìkà ò pé Gbogbo Mùtúnmùwà! Bó o bá ṣe é ree Wà á kẹ́san À’tore…
Ẹ Fèyí Kọ́gbọ́n Mo délé Alárá N ò gbọ́ poroporo odó Mo délé Ajerò N ò gbọ́ kọ̀ǹkọ̀ṣọ̀ ajọ̀ Mo délé Ọwárọ̀gún-àga Bákan náà lọmọọ́…
Àyàjọ́ Falẹ! À ń gbòròmọdiẹ lọ́wọ́ ikú Tonídìí ní í dà nígbẹ̀yìn bídìí bàjẹ́ Ó tún ti ṣẹ̀ bó ti ń sẹ̀ Ó tún ti…
Ìwé Le! Túlẹ̀, ẹ sáré wá Akẹ́kọ̀ọ́, ẹ wá gbọ́ nàsíà Òkun kì í hó ruru Ká wà á ruru, àwé! Ìwé le lorin tí…
Agbẹ́kẹ̀lé Ènìyàn Mo gbọ́ pé ayé wà Mo múra èrò ìjìnlẹ̀ Mo rí i pẹ́dàá ń ráyé lò Mo múra, ó di dúnníyàn Mo wá…
ỌJÀ LAYÉ ỌJÀ LAYÉ Ọjà layé ọ̀rẹ́ mìi, Ọjà layé ará. Gbogbo ọmọ adáríhunrun pátá lówá nájà láyé, Dandan sì ni ká padà s'ílé e…
Ìdùnnú a ṣubú lu ayọ̀ Lọ́jọ́ a bá bímọ tuntun sáyé Tẹbítará a kí túńfúlù káàbọ̀. Bọ́jọ́ ṣe ń gorí ọjọ́ Tóṣù ń gorí oṣù…
Dèbórà, Obìnrin Ogun Ìmísí: Ìwé nípa ìgbésí ayé Àyìnlá Ọmọ Wúrà Ìwé tó kọ nípa a rẹ̀ kìí ṣé mímọ́ Bíkòṣe ti mímọ̀— Ìmọ̀ ogun.…