Ọjọ́ tí mo ti ń fi àwo òyìnbó jẹun kò fọ́ mọ́ mi lọ́wọ́ rí. Ohun tí ènìyàn kúkú ń ṣe nìyí náà ní…
Inú títa ló jí mi. Mo tilẹ̀ kọ́kọ́ rò pé àlá tí mo lá ni ó fà á ni – èèyàn ò gbọdọ̀ jẹ ata…
Kò sẹ́ranko bí kìnnìún níjù. Bó dolókìtì ẹni tí ó ṣe bí ọ̀bọ ò sí. Ẹranko tí ó sọ pé kí ìkookò ó dákẹ́ Wọ́n…
Ẹnìkan Ò Layé Ẹni ayé ńṣe maràba fún ó sọ́ra fẹ́nu aráyé Ẹ wí fún gbogbo molegòkè-molesọ̀ pé mo ní kí wọ́n rọra Gbogbo ẹni…
Ọmọ mí Mo bá wọn ná'jà Akẹ̀ẹ̀sán Mo bá wọn pé lọ́jà Orísúnbáre Ohun mò ń wá di tíntín abẹ́rẹ́ tó sọnù Mo wẹ'dò mẹ́fà,…
Mo lé téńté sórí igi odán mobojú wolẹ̀ láti wo àwọn ẹ̀dá tí Elédùmarè dá sílé Ayé À'teku, à'teye, àti omo adáríhurun ọ̀rọ̀ ilé ayeé…
Ọmọ bíbí ìlú Ifón ni Abíọ́dún; ó sì fẹ́ràn ìlú rẹ̀ púpọ̀. Ọkàn ò jọ̀kan ẹ̀bùn ni Olódùmarè fi jíǹkí Abíọdún. Orí rẹ pé púpò;…
Coro ló pojú kòró jẹ Ṣebí láti ọjọ́ táláyé ti dáyé L'ayé tí ń yí, tí ọmọ adáríhunrun ti ń yí tẹ̀le. Àfìgbà tí Coro…
Apá Kiní Emọ́ kú ojú òpó dí Eésùn là, o là dànù Ọ̀pálánbá ọtí èèbó fọ́ Onígbá sọọ́ kò ri sọ Ta ń mọ bi…
À-pè-kánukò Àpèkánukò! Àpèṣ'ẹnu ṣùùtì Bí-i músù ú rẹ́ja nínú ike. Owó ní í jẹ́bẹ̀, ìwọ ọ̀rẹ́, Bí kò bá sí nílé, Ẹ má wúlẹ̀ d'ọ́rọ̀…