Àtẹ́lẹwọ́

Ìwé ìròyìn náà

Àkójọpọ̀ àwọn lẹ́tà Yorùbá tí ó wà láàyè.

A máa ń tẹ̀ ẹ́ jáde ní ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀. Ka ní àkókò tó bá ọ lára ​​mu.

I Ènìyàn bí reluwé ni Alàgbà Sálù Jẹ́nwítèmi; kò ṣeé kọlù, bẹ́ẹ̀ni kò sì gbọ́dọ̀ kọlu ènìyàn. Kì í see […]

Láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀, ọ̀kan gbòógì nínú ìdí tí a fi dá ÀTẸLẸWỌ sílẹ̀ ní ọdún 2017 ni títẹ ìwé jáde […]

Gbogbo rògbòdìyàn tó ń lọ ní’gboro tojú sú ni pátápátá.Tí t’ arúgbó t’omidan fi ń sá hílà-híloTí ìbẹ̀rù ìṣẹ́ òhun […]

Àwọn ènìyàn ìlú mi ńlá àwọn ìka wọ̀bìà wọ́n mọ́níbi ẹ̀jẹ̀ tó ń tọ jádepẹ̀lú ìgbàgbé pé ìka àárínń padà […]

Adé-ìmọ́lẹ̀ náà wúwo lórí ẹni mímọ́ náà, Ó rúnjúpọ̀ fún àpọ̀jù-ìmọ́lẹ̀tó wọ̀ ọ́ lójú, ó ti kó ṣáwùjọ̀ aláìrọ́runwọ̀. a […]

Ìfarajìn Fún D Eléyìí le wá sópin ní àwọn ọ̀nà méjì Pẹ̀lú rẹ, Mo fẹ́ èyí tó dára –Níbi tó […]

Igúnnugún bà lórùléOjú kálé, Ojú káko. Òrí akéwì kò ní jábọ́ Kó má yí nǹkan. Kí láǹfààní orógbó? A pa […]

Nígbà kan rí, àwọn ẹranko kéréjekéréje bi Eèrà, Ìjàlọ, Eku, Aáyán, Ikán àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ yan Ìjàlọ kó máa […]

Lati ọwọ́ọ Wálé Adébánwi, Akin Adéṣọ̀kàn, Tádé Ìpàdéọlá, Ebenezer Ọbádáre, àti Oyèníyì Òkúnoyè. Ni nǹkan bíi ọdún mẹ́fà sẹ́yìn ni […]

Ìtìjú Dà? Àyìndé dé tòhun tàròfọ̀ Orí Àyìndé ò ní balẹ̀ Kó má mà yí nǹkan. Ohun ojú akéwì ń […]

Ayé yìí ò le Pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ lejò ń gàgbọn. Ayé yìí ò gba gìrìgìrì Lọ̀gà fi ń tẹlẹ̀ jẹ́jẹ́jẹ́. Ẹ̀sọ̀ pẹ̀lẹ́ […]

Ìtàn àròsọ yìí dálé ìtàn ìsẹ̀dálẹ̀ ìlú kan tí à ń pè ní ILÉ-OGBÓ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun, ILÉ-OGBÓ wà ní […]