Àtẹ́lẹwọ́

…ìràpadà, ìsọjí, ìtúntò

  • Ojúde-Àkọ́kàn
  • Ìgbàwọlé
  • Ewì
  • Àpilẹ̀kọ
  • Eré
  • Àwòrán
  • Ìtàn
  • Ìròyìn
  • Àṣàyàn Olóòtú

Home /Atelewo
Aáyan ògbufọ̀

Ìrírí Òbí Àti Ìtọ́jú Ọmọ Nínú “Ìgbà Èwe” Láti Ọwọ́ Kọ́lá Túbọ̀sún | Rasaq Malik Gbọ́láhàn

August 10, 2021 0

Àkọ́lé Ìwé: Ìgbà Èwe (Childhood)Ònkọ̀wé: Emily R. Grosholz Olùtúmọ̀ sí Èdè Yorùbá: Kọ́lá Túbọ̀sùnỌdún Tó Jáde: 2021Olùtẹ̀wé: Ouida BooksISBN: 978-978-990-701-4 Ní ayé òde òní, ìgbéga…

Àpilẹ̀kọ

Ìkòríta Mẹ́ta |Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀

March 19, 2021 1

Ìlẹ̀kẹ̀ má jà á sílé má jà á síta ibì kan ni yóò já sí lọ́jọ́ kan. Dùnúnkẹ́ rẹwà lọmọ. Ó pupa bí àsáró elépo.…

Àṣàyàn Olóòtú

B’ọ́bẹ̀ ẹ bá dùn àti ewì míràn | Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀

March 19, 2021 0

Olú ti d'ẹ́nu ní ìbúǹbú Ó di dandan kó jẹun. Ebi kìí wọnú kọ́rọ̀ míì ó wọ̀ ọ́ Òrìṣà bí ọ̀fun ò sí tipẹ́tipẹ́ Joojúmọ́ ní ń gbẹbọ lọ́wọ́…

Ewì

Ọmọ Òrukàn àti ewì míràn | Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀

January 22, 2021 0

ỌMỌ ÒRUKÀN Ikọ́ wíwú ológìnní kìí ṣàfiṣe Ìran baba wọn níí wúkọ́ fee. Gbígbó ajá kì í kúkú pajá. Ìran wọn ló ní gbígbó. A…

Ewì

Jẹgúdújẹrá àti ewì míràn | Ayọ̀bámi Káyòdé

January 13, 2021 0

Ẹ̀rù àwọn ará ibí bà mí jọjọ. Ẹrù àìbìkítà wọn a máa ṣe mí bí ọyẹ́ ti ń ṣe ọmọ ìkókó. À ṣé ọdẹ tí…

Ewì

Bá Ò kú | Rodiyah Ọmọ́tọ́yọ̀sí Mikail

January 1, 2021 0

Ṣóo wo iwájú tóò r’ẹ́nìkan  O w’ẹ̀yìn wò, óò r’éèyàn L’ọ́tùn-ún l’ósì, ilẹ̀ tẹ́ lọ bẹẹrẹ Àṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, o ní ikú ló kàn Ọjọ́ a…

Ìtàn

Ibi Orí Dá’ni Sí Làágbé | Lanase Hussein

December 29, 2020 0

Òpóǹló ni mo wà tí mo ti máa ń gbọ́ nípa ìlú Èkó. Oríṣiríṣi ni atilẹ̀ máa ń gbọ́ ni ìgbà náà. Àwọn kan àtilẹ̀…

Posts pagination

prev 1 … 4 5

ÀTẸ́LẸWỌ́

ÀTẸ́LẸWỌ́ jẹ́ àjọ tí ò wà láti gbé Yorùbá dìde àti láti tún iṣẹ́ Yorùbá tò. Àwọn àfojúsùn wa jẹ́: 1. Láti pèṣè ibi tí àwọn akẹ́kọ̀ ati ọ̀dọ́ leé máa kopa pẹlú oríṣiríṣi ẹya aṣa àti ìṣe Yorùbá látàrí ìdíje, ẹ̀kọ́, ìfọ̀rọ̀jomítoro ọ̀rọ̀ ati ṣi ṣe ìpàdé déédé. 2. Láti ṣe àgbékalẹ̀ ibi tí a ti má ṣe àkọsílẹ̀ ati ìpamọ òye àṣà Yorùbá ìgbà àtẹ̀yìnwá àti láti máá lo ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé fún ìdàgbàsókè àṣà wa. 3. Tí ta àwọn èyàn jí sí ìfẹ́ lítíreṣọ̀ Yorùbá latàrí ṣiṣe ètò ìwé kíkà, jíjẹ kí ìwé lítíreṣọ̀ Yorùbá wà nlẹ̀ fún tità àti ṣíṣe àtẹ̀jade àwọn oǹkọ̀wé titun ní èdè Yorùbá.


Contact us: egbeatelewo@gmail.com

  • Ilé
  • Nípa Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìdíje Ìwé Kíkọ
  • Ikọ̀
  • Àtẹ̀jáde
  • Ètò Ìwé Kíkà
  • Ògbóǹtarìgì: A Docuseries Project to Celebrate Old Veteran Yorùbá Authors
  • Kíni Wọ́n ń Sọ
  • Ètò
  • Ẹ kàn sí wa
  • Aáyan ògbufọ̀
  • Àpilẹ̀kọ
  • Àṣàyàn Olóòtú
  • Àwòrán
  • Eré
  • Ewì
  • Fídíò
  • Ìròyìn
  • Ìtàn
  • Ìtàn
  • Ìtàn Àròsọ
  • Ìtọ́wò Ìwé Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìwádìí
  • Lẹ́tà
  • News
  • Oguso
  • Orin
  • Ọ̀rọ̀ Ìlú
  • Rìfíù Ìwé
  • Uncategorized