Nínú ọ̀rọ̀ ìṣáájú fún ìwé ‘Adéjọké ará Ìjílèje—Àkójọpọ̀ ìtàn kéékèèké Adébáyọ Fálétí,’ Òjọgbọ́n Ọlátúndé O. Ọlátúnjí kọ wípé: “Àwọn ọmọdé ni Adébáyọ Fálétí fi perí…
A dúpẹ́ fún àwọn ohun tí ẹ fi ṣowọ́ sí wa fun àtẹ̀jade Kínní. Àtẹ̀jade kejì yíò jẹ́ ìfisorí fún àwọn àgbà oǹkọ̀wé mẹ́ta tí…
Bàbá afọ́jú kan wà tí ó máa ń kọjá níwájú ilé wa nígbà tí mo wà ní kékeré. Ó dúdú àmọ́ irùngbọ̀n rẹ̀ funfun báláú.…
Ẹ forí jìn mí o, ẹ̀yin tí è ń gbé inú ilé yí. Ẹ̀rù ajá yín tí ó ń bà mí ni mo ṣe kọ…
Moti dé'lé ayé ọjọ́ ti pẹ́, Moti d'ókè eèpẹ̀ ọ̀nà ti jì, Ṣebí ojúlarí ọ̀rẹ́ ò dénú. Ṣààsà ènìyàn ní fẹ́'ní lẹ́yìn táà bá sí…
Gbogbo ohun tí a bá ṣe lónìí, ọ̀rọ̀ ìtàn ni bó dọ̀la Gbogbo ayé ló máa tán Gbogbo wa la máa padà dìtàn. Nítàn kí…
Ọ̀RÒ ÌṢÁÁJÚ “Ìbẹ̀rẹ̀ kìí ṣe oníṣẹ́, èèyàn tó bá fi orí tìí d’ópin ni a ó gbàlà”, jẹ́ oun tí wọ́n maa ń sọ. Inú…
Bí mo ṣe gbọ́ ìbéérè tí Dádì béèrè lọ́wọ́ mi, ṣe ni mo fi ẹ̀rín tó fẹ́ wú jáde lẹ́nu mi pamọ́ sí ẹ̀rẹ̀kẹ́. Ṣè…
Ẹsẹ̀ Kiní Kíni mofẹ́ ṣe láì sí ẹnu rẹ Nì tí ó jáfáfá Tí ó ń fà mí mọra, ti ìwọ sì ń tamí sí…
MÀÁMI Ọ̀WỌ́N Màámi ọ̀wọ́n, Ìdùnú àti àyọ̀ ni mo fi kọ ìwé yìí. Báwo ni ǹkàn? Gbogbo ilé ńkọ́? Ṣe ẹ̀ ń tà, ṣ’ájé ń…