Ẹni Bá Ń Yọ́lẹ̀ Ẹ́ Dà | Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀
Òru là ń ṣèkà ẹni tó ṣe lọ́sàn-án kò fara rere lọ. Ilẹ̀ ti ta sí i ti àwọn ọmọ […]
Òru là ń ṣèkà ẹni tó ṣe lọ́sàn-án kò fara rere lọ. Ilẹ̀ ti ta sí i ti àwọn ọmọ […]
Ta Ni Kí Ń Bi? Mo wò òréré ayé yíká Ayé ò yé mí rárá Mo wò sánmọ̀ lọ súà
Bí aré kò bá tó aré a kì í pòwe, bí ọ̀rọ̀ kò bá tọ́rọ̀ a kìí fìtàn balẹ̀, bí
Ìlẹ̀kẹ̀ má jà á sílé má jà á síta ibì kan ni yóò já sí lọ́jọ́ kan. Dùnúnkẹ́ rẹwà lọmọ.
Olú ti d’ẹ́nu ní ìbúǹbú Ó di dandan kó jẹun. Ebi kìí wọnú kọ́rọ̀ míì ó wọ̀ ọ́ Òrìṣà bí ọ̀fun ò sí
ỌMỌ ÒRUKÀN Ikọ́ wíwú ológìnní kìí ṣàfiṣe Ìran baba wọn níí wúkọ́ fee. Gbígbó ajá kì í kúkú pajá. Ìran
Jòjòló akéwì tún dé Mo fẹ́ kọrin ewì sétí aráyé Ẹ yá mi létí yín. Ọ̀rọ̀ fẹ́ máa jábọ́ bí
Ọjọ́ tí mo ti ń fi àwo òyìnbó jẹun kò fọ́ mọ́ mi lọ́wọ́ rí. Ohun tí ènìyàn kúkú
Kò sẹ́ranko bí kìnnìún níjù. Bó dolókìtì ẹni tí ó ṣe bí ọ̀bọ ò sí. Ẹranko tí ó sọ pé