Ẹnìkan Ò Layé Ẹni ayé ńṣe maràba fún ó sọ́ra fẹ́nu aráyé Ẹ wí fún gbogbo molegòkè-molesọ̀ pé mo ní kí wọ́n rọra Gbogbo ẹni…
Ọmọ mí Mo bá wọn ná'jà Akẹ̀ẹ̀sán Mo bá wọn pé lọ́jà Orísúnbáre Ohun mò ń wá di tíntín abẹ́rẹ́ tó sọnù Mo wẹ'dò mẹ́fà,…
Mo lé téńté sórí igi odán mobojú wolẹ̀ láti wo àwọn ẹ̀dá tí Elédùmarè dá sílé Ayé À'teku, à'teye, àti omo adáríhurun ọ̀rọ̀ ilé ayeé…
Ẹ Bọ̀wọ̀ F’ágbà “Ajá tó r’ólówó ẹ̀ rojú, kín ní ó f’ólówó è se kò tié yé mi.” —Éégunmọgají Àyìnlá Ọmọwúrà. Ìrírí kí lọmọdé ní,…
Nípa wíwà àti nínú Òfo Bó bá pẹ́ títí Ọmọ ènìyàn á ṣ'àfẹ́rí irẹ rẹ̀ lọ sí ònà jíjìn. Ó só síni lẹ́nu, mo sí…
Coro ló pojú kòró jẹ Ṣebí láti ọjọ́ táláyé ti dáyé L'ayé tí ń yí, tí ọmọ adáríhunrun ti ń yí tẹ̀le. Àfìgbà tí Coro…
Apá Kiní Emọ́ kú ojú òpó dí Eésùn là, o là dànù Ọ̀pálánbá ọtí èèbó fọ́ Onígbá sọọ́ kò ri sọ Ta ń mọ bi…
Egbìrìn ọ̀tẹ̀ bí à ń ṣé pa ìkan ni ọ̀kan rú ní ìlú mi. Ní àgbàlá òdòdó yìí ẹ̀gún ń wù lára ènìyàn, Ìlú yìí…
Orí l'atọ́kùn ara, Olóòótọ́ tí ń darí ìwà, Awakọ̀ ti kii sìnà l'ójú 'gbó, Orí mi gbé mi dé bi ire. Orí ni apẹja tí…
À-pè-kánukò Àpèkánukò! Àpèṣ'ẹnu ṣùùtì Bí-i músù ú rẹ́ja nínú ike. Owó ní í jẹ́bẹ̀, ìwọ ọ̀rẹ́, Bí kò bá sí nílé, Ẹ má wúlẹ̀ d'ọ́rọ̀…