Gbogbo rògbòdìyàn tó ń lọ ní’gboro tojú sú ni pátápátá.Tí t’ arúgbó t’omidan fi ń sá hílà-híloTí ìbẹ̀rù ìṣẹ́ òhun òṣì fi ń mú t’ẹru…
Adé-ìmọ́lẹ̀ náà wúwo lórí ẹni mímọ́ náà, Ó rúnjúpọ̀ fún àpọ̀jù-ìmọ́lẹ̀tó wọ̀ ọ́ lójú, ó ti kó ṣáwùjọ̀ aláìrọ́runwọ̀. a gbe dè sórí àpèré,Òrìṣà náà…
Ìfarajìn Fún D Eléyìí le wá sópin ní àwọn ọ̀nà méjì Pẹ̀lú rẹ, Mo fẹ́ èyí tó dára –Níbi tó jẹ́ pé a ti ń…
Igúnnugún bà lórùléOjú kálé, Ojú káko. Òrí akéwì kò ní jábọ́ Kó má yí nǹkan. Kí láǹfààní orógbó? A pa á, kò láwẹ́ A jẹ́,…
Nígbà kan rí, àwọn ẹranko kéréjekéréje bi Eèrà, Ìjàlọ, Eku, Aáyán, Ikán àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ yan Ìjàlọ kó máa ṣe olorí wọn. Wọ́n ṣe…
Lati ọwọ́ọ Wálé Adébánwi, Akin Adéṣọ̀kàn, Tádé Ìpàdéọlá, Ebenezer Ọbádáre, àti Oyèníyì Òkúnoyè. Ni nǹkan bíi ọdún mẹ́fà sẹ́yìn ni àwọn ònkọ̀wé yìí sowọ́pọ̀ kọ…
Ayé yìí ò le Pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ lejò ń gàgbọn. Ayé yìí ò gba gìrìgìrì Lọ̀gà fi ń tẹlẹ̀ jẹ́jẹ́jẹ́. Ẹ̀sọ̀ pẹ̀lẹ́ ló láyé Dúníyàn ò fẹ́…
Ìtàn àròsọ yìí dálé ìtàn ìsẹ̀dálẹ̀ ìlú kan tí à ń pè ní ILÉ-OGBÓ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun, ILÉ-OGBÓ wà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀sun ibẹ̀ náà sì…
Ẹ jógun ó mí, ẹ ṣìmẹ̀dọ̀ n’ìyáàlù ń ké. Àmọ́ ọ̀rọ Nìjéè só síni lẹ́nu, ó tún buyọ̀ si. Iyọ̀ àlàáfíà ò sé tu dànù…
Ẹni tí yóò bá pẹ̀gàn àjànàkú ni yóò sọ pé òun rí nǹkan fìrí. Igi pọ̀ nígbó àmọ́ ọ̀tọ̀ ni igi ọ̀mọ̀. Kòkòrò pégba nígbó…