Àtẹ́lẹwọ́

…ìràpadà, ìsọjí, ìtúntò

  • Ojúde-Àkọ́kàn
  • Ìgbàwọlé
  • Ewì
  • Àpilẹ̀kọ
  • Eré
  • Àwòrán
  • Ìtàn
  • Ìròyìn
  • Àṣàyàn Olóòtú

Àpilẹ̀kọ

Home /Àpilẹ̀kọ
Àpilẹ̀kọ

Kọ̀lọ̀rọ̀sí | Khadijah Ọlájùmọ̀kẹ́ Kọ́lápọ̀

August 3, 2020 0

Inú títa ló jí mi. Mo tilẹ̀ kọ́kọ́ rò pé àlá tí mo lá ni ó fà á ni – èèyàn ò gbọdọ̀ jẹ ata…

Àpilẹ̀kọ

Ẹni Ìjà Ò Bá |Gàníyù Saheed Ìṣọ̀lá

July 6, 2020 0

Ọmọ bíbí ìlú Ifón ni Abíọ́dún; ó sì fẹ́ràn ìlú rẹ̀ púpọ̀. Ọkàn ò jọ̀kan ẹ̀bùn ni Olódùmarè fi jíǹkí  Abíọdún. Orí rẹ pé púpò;…

Àpilẹ̀kọ

Ewì ní ìrántí Adébáyọ̀ Fálétí, Akínwùmí Ìṣọ̀lá, àti Ọládẹ̀jọ Òkédìjí |Kọ́dáolú Tolúlọpẹ́

June 20, 2020 0

Apá Kiní Emọ́ kú ojú òpó dí Eésùn là, o là dànù Ọ̀pálánbá ọtí èèbó fọ́ Onígbá sọọ́ kò ri sọ Ta ń mọ bi…

Àpilẹ̀kọ

Ḱíkorò Ewúro àti Àwọn Ewì Méjì Míràn |Ìyanuolúwa Adénlé

May 20, 2020 0

Kíkorò Ewúro Gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Adùn ló yẹ kí ó gbẹ̀yìn ewúro Ṣùgbọ́n kò sẹ́ni tí ó ń Bèrè nípa kíkorò tí ewúro…

Àpilẹ̀kọ

Akéwì Àti Ewì Míràn | Ṣégun Ṣóẹ̀tán

May 20, 2020 0

Akéwì Èmi lakéwì, mo lóyin létè. Mo kẹ̀tẹ̀ǹfẹ̀ ìmọ̀ Mo le sọrọ́ dòótọ́ bí n bá fẹ́! Bó wù mí, mo le sòótọ́ dòbu Ajá…

Àpilẹ̀kọ

Ẹ̀rọ Ìránsọ | Kọ́lápọ̀ Ọlájùmọ̀kẹ́

October 1, 2019 0

Bàbá afọ́jú kan wà tí ó máa ń kọjá níwájú ilé wa nígbà tí mo wà ní kékeré. Ó dúdú àmọ́ irùngbọ̀n rẹ̀ funfun báláú.…

Àpilẹ̀kọ

Lẹ́tà: Ọ̀rọ̀ Kẹ̀kẹ́ | ‘Gbénga Adéọba

October 1, 2019 0

Ẹ forí jìn mí o, ẹ̀yin tí è ń gbé inú ilé yí. Ẹ̀rù ajá yín tí ó ń bà mí ni mo ṣe kọ…

Àpilẹ̀kọ

Ìbéérè Oyún| Kàfí Fáshọlá

April 19, 2019 0

Bí mo ṣe gbọ́ ìbéérè tí Dádì béèrè lọ́wọ́ mi, ṣe ni mo fi ẹ̀rín tó fẹ́ wú jáde lẹ́nu mi pamọ́ sí ẹ̀rẹ̀kẹ́. Ṣè…

Àpilẹ̀kọ

Lẹ́tà Méjì |Mof’Ólúwawò O MojọláOlúwa

March 20, 2019 1

MÀÁMI Ọ̀WỌ́N Màámi ọ̀wọ́n, Ìdùnú àti àyọ̀ ni mo fi kọ ìwé yìí. Báwo ni ǹkàn? Gbogbo ilé ńkọ́? Ṣe ẹ̀ ń tà, ṣ’ájé ń…

Àpilẹ̀kọ

Kílẹ̀ Tó Pòṣìkà |Rasaq Malik Gbọ́láhàn

February 9, 2019 1

Ní ojoojúmọ́ ayé mi ni mo máá ń ronú nípa ayé àwa ẹ̀dá, nípa àditú ayé tí ó ń fi ìgbà gbogbo ṣ’emí ní kàyéfì.…

Posts pagination

prev 1 2 3 4 next

ÀTẸ́LẸWỌ́

ÀTẸ́LẸWỌ́ jẹ́ àjọ tí ò wà láti gbé Yorùbá dìde àti láti tún iṣẹ́ Yorùbá tò. Àwọn àfojúsùn wa jẹ́: 1. Láti pèṣè ibi tí àwọn akẹ́kọ̀ ati ọ̀dọ́ leé máa kopa pẹlú oríṣiríṣi ẹya aṣa àti ìṣe Yorùbá látàrí ìdíje, ẹ̀kọ́, ìfọ̀rọ̀jomítoro ọ̀rọ̀ ati ṣi ṣe ìpàdé déédé. 2. Láti ṣe àgbékalẹ̀ ibi tí a ti má ṣe àkọsílẹ̀ ati ìpamọ òye àṣà Yorùbá ìgbà àtẹ̀yìnwá àti láti máá lo ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé fún ìdàgbàsókè àṣà wa. 3. Tí ta àwọn èyàn jí sí ìfẹ́ lítíreṣọ̀ Yorùbá latàrí ṣiṣe ètò ìwé kíkà, jíjẹ kí ìwé lítíreṣọ̀ Yorùbá wà nlẹ̀ fún tità àti ṣíṣe àtẹ̀jade àwọn oǹkọ̀wé titun ní èdè Yorùbá.


Contact us: egbeatelewo@gmail.com

  • Ilé
  • Nípa Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìdíje Ìwé Kíkọ
  • Ikọ̀
  • Àtẹ̀jáde
  • Ètò Ìwé Kíkà
  • Ògbóǹtarìgì: A Docuseries Project to Celebrate Old Veteran Yorùbá Authors
  • Kíni Wọ́n ń Sọ
  • Ètò
  • Ẹ kàn sí wa
  • Aáyan ògbufọ̀
  • Àpilẹ̀kọ
  • Àṣàyàn Olóòtú
  • Àwòrán
  • Eré
  • Ewì
  • Fídíò
  • Ìròyìn
  • Ìtàn
  • Ìtàn
  • Ìtàn Àròsọ
  • Ìtọ́wò Ìwé Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìwádìí
  • Lẹ́tà
  • News
  • Oguso
  • Orin
  • Ọ̀rọ̀ Ìlú
  • Rìfíù Ìwé
  • Uncategorized