Ìyá kogberegbe, ní gbogbo ara àdúgbò mọ ó si, àmọ́ ìyá èkó ni àwọn ẹbí ń pè é. Kii dá rìn lai si ìyá Dupẹ.…
Mo ti pàdé ọ̀pọ̀ ènìyàn ní ìwọ̀n ọdún tí mo tì lò láyé, sùgbọ́n sàsà ni èyí tí ó nípa bíi bàbá Àmọ̀pé. Ọkùnrin mẹ́ta…
Ẹ̀rọ Omi Báwo ni ó máa ń rí l’ára nígbà tí o bá ń gbìyànjú àti gba ẹlòmíràn là tí ìwọgan an wá di ẹni…
È̩RÍN ÀRÍNTÀKÌTÌ L’ÉKÌTÌ Ìpínlè̩ Èkìtì jé̩ ò̩kan pàtàkì lára àwo̩n ìpínlè̩ t íÌjo̩ba Ológun dásílè̩ ní 1996 lábé̩ ìs̩è jo̩ba Ò̩gágun Sanni Abacha. Láti ara…
ÒWE Ọsán já ọrún d’ọ̀pá. ÀKÍYÈSÍ *Ọsán:- ohun èlò tí a fi ún se ǹkan ìjà tí a mò sí ọfà *Ọrún:- orísi ọ̀pá kan…
Ojú lọ̀rọ́ wà, ètè kọ́ Ojú lọ̀rọ́ wà, ète lẹnu Ojú lọ̀rọ́ wà, ète lètè Ojú lọ̀rọ́ wà, ète lẹnu –Èdè ẹnu fun ìlù u…
Yorùbá bọ̀ wón ní báyé ba ń yí kámáa bá’yé yí, bí ìgbà báńyí ká máa bá ìgbà yi torí ẹni tí kò bá bágbàyí…