Ḱíkorò Ewúro àti Àwọn Ewì Méjì Míràn |Ìyanuolúwa Adénlé
Kíkorò Ewúro Gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Adùn ló yẹ kí ó gbẹ̀yìn ewúro Ṣùgbọ́n kò sẹ́ni tí ó ń […]
Kíkorò Ewúro Gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Adùn ló yẹ kí ó gbẹ̀yìn ewúro Ṣùgbọ́n kò sẹ́ni tí ó ń […]
Akéwì Èmi lakéwì, mo lóyin létè. Mo kẹ̀tẹ̀ǹfẹ̀ ìmọ̀ Mo le sọrọ́ dòótọ́ bí n bá fẹ́! Bó wù mí,
Nínú ọ̀rọ̀ ìṣáájú fún ìwé ‘Adéjọké ará Ìjílèje—Àkójọpọ̀ ìtàn kéékèèké Adébáyọ Fálétí,’ Òjọgbọ́n Ọlátúndé O. Ọlátúnjí kọ wípé: “Àwọn ọmọdé
A dúpẹ́ fún àwọn ohun tí ẹ fi ṣowọ́ sí wa fun àtẹ̀jade Kínní. Àtẹ̀jade kejì yíò jẹ́ ìfisorí fún
Bàbá afọ́jú kan wà tí ó máa ń kọjá níwájú ilé wa nígbà tí mo wà ní kékeré. Ó dúdú
Ẹ forí jìn mí o, ẹ̀yin tí è ń gbé inú ilé yí. Ẹ̀rù ajá yín tí ó ń bà
Moti dé’lé ayé ọjọ́ ti pẹ́, Moti d’ókè eèpẹ̀ ọ̀nà ti jì, Ṣebí ojúlarí ọ̀rẹ́ ò dénú. Ṣààsà ènìyàn ní
Gbogbo ohun tí a bá ṣe lónìí, ọ̀rọ̀ ìtàn ni bó dọ̀la Gbogbo ayé ló máa tán Gbogbo wa la
Ọ̀RÒ ÌṢÁÁJÚ “Ìbẹ̀rẹ̀ kìí ṣe oníṣẹ́, èèyàn tó bá fi orí tìí d’ópin ni a ó gbàlà”, jẹ́ oun tí
Bí mo ṣe gbọ́ ìbéérè tí Dádì béèrè lọ́wọ́ mi, ṣe ni mo fi ẹ̀rín tó fẹ́ wú jáde lẹ́nu