Ìwà l’ẹwà | Adéṣínà Àjàlá
Ọmọ mí Mo bá wọn ná’jà Akẹ̀ẹ̀sán Mo bá wọn pé lọ́jà Orísúnbáre Ohun mò ń wá di tíntín abẹ́rẹ́ […]
Ọmọ mí Mo bá wọn ná’jà Akẹ̀ẹ̀sán Mo bá wọn pé lọ́jà Orísúnbáre Ohun mò ń wá di tíntín abẹ́rẹ́ […]
Mo lé téńté sórí igi odán mobojú wolẹ̀ láti wo àwọn ẹ̀dá tí Elédùmarè dá sílé Ayé À’teku, à’teye, àti
Ẹ Bọ̀wọ̀ F’ágbà “Ajá tó r’ólówó ẹ̀ rojú, kín ní ó f’ólówó è se kò tié yé mi.” —Éégunmọgají Àyìnlá
Ọmọ bíbí ìlú Ifón ni Abíọ́dún; ó sì fẹ́ràn ìlú rẹ̀ púpọ̀. Ọkàn ò jọ̀kan ẹ̀bùn ni Olódùmarè fi jíǹkí
Nípa wíwà àti nínú Òfo Bó bá pẹ́ títí Ọmọ ènìyàn á ṣ’àfẹ́rí irẹ rẹ̀ lọ sí ònà jíjìn. Ó
Coro ló pojú kòró jẹ Ṣebí láti ọjọ́ táláyé ti dáyé L’ayé tí ń yí, tí ọmọ adáríhunrun ti ń
Apá Kiní Emọ́ kú ojú òpó dí Eésùn là, o là dànù Ọ̀pálánbá ọtí èèbó fọ́ Onígbá sọọ́ kò ri
Egbìrìn ọ̀tẹ̀ bí à ń ṣé pa ìkan ni ọ̀kan rú ní ìlú mi. Ní àgbàlá òdòdó yìí ẹ̀gún ń
Orí l’atọ́kùn ara, Olóòótọ́ tí ń darí ìwà, Awakọ̀ ti kii sìnà l’ójú ‘gbó, Orí mi gbé mi dé bi
À-pè-kánukò Àpèkánukò! Àpèṣ’ẹnu ṣùùtì Bí-i músù ú rẹ́ja nínú ike. Owó ní í jẹ́bẹ̀, ìwọ ọ̀rẹ́, Bí kò bá sí