Ẹ̀yin Ònkàwé, Ẹ kú u dédé àsìkò yìí o ẹ̀yin òǹkàwé wa, a sì kú ìpalẹ̀mọ́ pọ̀pọ̀ṣìnṣìn odún tuntun tó ń bọ̀ lọ́nà. Èyí ni…
Ìtan Arìnrìn-àjò kan/ The Child’s story Ìtan Arìnrìn-àjò kan Ní àkókò kan ṣẹ́yìn, ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún tí ó dára ṣẹ́yìn. Arìnrìn-àjò kan-án wà, tí ó…
Ní ìlú kan tí à ń pè ní Bíkú, Bí-ikú-ilé-ò-pa-ni ni àjápè orúkọ ìlú yìí ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn fẹ́ràn láti máa ge kúrú sí…
Àyàjọ́ Falẹ! À ń gbòròmọdiẹ lọ́wọ́ ikú Tonídìí ní í dà nígbẹ̀yìn bídìí bàjẹ́ Ó tún ti ṣẹ̀ bó ti ń sẹ̀ Ó tún ti…
Ìwé Le! Túlẹ̀, ẹ sáré wá Akẹ́kọ̀ọ́, ẹ wá gbọ́ nàsíà Òkun kì í hó ruru Ká wà á ruru, àwé! Ìwé le lorin tí…
Agbẹ́kẹ̀lé Ènìyàn Mo gbọ́ pé ayé wà Mo múra èrò ìjìnlẹ̀ Mo rí i pẹ́dàá ń ráyé lò Mo múra, ó di dúnníyàn Mo wá…
Okùn Ìfẹ́ Yi! Ìfẹ́ pọ́gbọ̀n, ó jọgbọ̀n Ìfẹ̀ pégba, ó jugba Ìfẹ́ pérínwó, ó jurínwó Ìfẹ́ẹ̀fẹ́ táyé fẹ́lá lóko Kò ju kí wọ́n ríhun filá…