Àtẹ́lẹwọ́

…ìràpadà, ìsọjí, ìtúntò

  • Ojúde-Àkọ́kàn
  • Ìgbàwọlé
  • Ewì
  • Àpilẹ̀kọ
  • Eré
  • Àwòrán
  • Ìtàn
  • Ìròyìn
  • Àṣàyàn Olóòtú

Tags archive: Yoruba

Home /Tag:Yoruba
Àpilẹ̀kọ

Ikú Ń Jọ̀gẹ̀dẹ̀ | Ọláyàtọ̀ Ọláolúwa

March 19, 2024 0

Nígbà kan rí, àwọn ẹranko kéréjekéréje bi Eèrà, Ìjàlọ, Eku, Aáyán, Ikán àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ yan Ìjàlọ kó máa ṣe olorí wọn. Wọ́n ṣe…

Aáyan ògbufọ̀

Ní Ìrántí Akéwì Láńrewájú Adépọ̀jù

March 19, 2024 0

Lati ọwọ́ọ Wálé Adébánwi, Akin Adéṣọ̀kàn, Tádé Ìpàdéọlá, Ebenezer Ọbádáre, àti Oyèníyì Òkúnoyè. Ni nǹkan bíi ọdún mẹ́fà sẹ́yìn ni àwọn ònkọ̀wé yìí  sowọ́pọ̀ kọ…

Àpilẹ̀kọ

Ẹni Bá Ń Yọ́lẹ̀ Ẹ́ Dà | Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀

March 10, 2023 0

Òru là ń ṣèkà ẹni tó ṣe lọ́sàn-án kò fara rere lọ. Ilẹ̀ ti ta sí i ti àwọn ọmọ wòlìbísà tí ń ja àwọn…

Àṣàyàn Olóòtú

Káṣílẹ́sí  Pọlisì (Cash-Less Policy) | Akíntọ́lá Ismail Kọ́ládé

February 25, 2023 1

Ìlú kan gógó, Ilu òf'ara rọ Àwọn ará ìlú gaan ò rẹ́ẹ̀rín. Àṣe k'árówóná òdàbí k'álówó nílé k'álówó nílé gan-an òdàbí k’álówó lápò k’álówó lápò…

Aáyan ògbufọ̀

Ìrírí Òbí Àti Ìtọ́jú Ọmọ Nínú “Ìgbà Èwe” Láti Ọwọ́ Kọ́lá Túbọ̀sún | Rasaq Malik Gbọ́láhàn

August 10, 2021 0

Àkọ́lé Ìwé: Ìgbà Èwe (Childhood)Ònkọ̀wé: Emily R. Grosholz Olùtúmọ̀ sí Èdè Yorùbá: Kọ́lá Túbọ̀sùnỌdún Tó Jáde: 2021Olùtẹ̀wé: Ouida BooksISBN: 978-978-990-701-4 Ní ayé òde òní, ìgbéga…

Àṣàyàn Olóòtú

Káràkátà Àti Àwóran míràn |Awósùsì Olúwábùkúnmi

July 26, 2021 0

Káràkátà Mo ya àwòrán yìí ní ọdún 2020 nígbàtí àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 gbòde kan. Ìyàlẹ́nu ló jẹ fún mí nígbà tí mo ri ọ̀pọ̀ ènìyàn…

Àṣàyàn Olóòtú

Wèrè Alásọ àti Àwọn Ewì Míràn |Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀

July 26, 2021 0

Ta Ni Kí Ń Bi? Mo wò òréré ayé yíká Ayé ò yé mí rárá Mo wò sánmọ̀ lọ súà Kò yé mi bó ṣe…

Àpilẹ̀kọ

Lálẹ́ Ìgbéyàwó | Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀

July 26, 2021 0

Bí aré kò bá tó aré a kì í pòwe, bí ọ̀rọ̀ kò bá tọ́rọ̀ a kìí fìtàn balẹ̀, bí iṣẹ́ kò bá le a…

Àpilẹ̀kọ

Inúlayéwà Ọkọ Mọ́mbé | Lánasẹ̀ Hussein

July 26, 2021 1

Kò sí ẹnì kankan tí kò mọ Ìyá àgbà ní abàá Alẹ́mọ́, kìí sọ ìtàn kan ní ẹ̀ẹ̀mejì. Àgbà òpìtàn sì ni pẹ̀lú. Kò fẹ́…

Aáyan ògbufọ̀

Wíwá Ilé L’ájò |Adépọ̀jù Isaiah Gbénga

March 19, 2021 0

Ọ̀nà tí ó yá jù láti dá'ná sun ara ẹni Ni nípa fifi iná sí ilé ẹni. Òlùkọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì mi ló sọ wípé, Kí…

Posts pagination

1 2 … 6 next

ÀTẸ́LẸWỌ́

ÀTẸ́LẸWỌ́ jẹ́ àjọ tí ò wà láti gbé Yorùbá dìde àti láti tún iṣẹ́ Yorùbá tò. Àwọn àfojúsùn wa jẹ́: 1. Láti pèṣè ibi tí àwọn akẹ́kọ̀ ati ọ̀dọ́ leé máa kopa pẹlú oríṣiríṣi ẹya aṣa àti ìṣe Yorùbá látàrí ìdíje, ẹ̀kọ́, ìfọ̀rọ̀jomítoro ọ̀rọ̀ ati ṣi ṣe ìpàdé déédé. 2. Láti ṣe àgbékalẹ̀ ibi tí a ti má ṣe àkọsílẹ̀ ati ìpamọ òye àṣà Yorùbá ìgbà àtẹ̀yìnwá àti láti máá lo ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé fún ìdàgbàsókè àṣà wa. 3. Tí ta àwọn èyàn jí sí ìfẹ́ lítíreṣọ̀ Yorùbá latàrí ṣiṣe ètò ìwé kíkà, jíjẹ kí ìwé lítíreṣọ̀ Yorùbá wà nlẹ̀ fún tità àti ṣíṣe àtẹ̀jade àwọn oǹkọ̀wé titun ní èdè Yorùbá.


Contact us: egbeatelewo@gmail.com

  • Ilé
  • Nípa Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìdíje Ìwé Kíkọ
  • Ikọ̀
  • Àtẹ̀jáde
  • Ètò Ìwé Kíkà
  • Ògbóǹtarìgì: A Docuseries Project to Celebrate Old Veteran Yorùbá Authors
  • Kíni Wọ́n ń Sọ
  • Ètò
  • Ẹ kàn sí wa
  • Aáyan ògbufọ̀
  • Àpilẹ̀kọ
  • Àṣàyàn Olóòtú
  • Àwòrán
  • Eré
  • Ewì
  • Fídíò
  • Ìròyìn
  • Ìtàn
  • Ìtàn
  • Ìtàn Àròsọ
  • Ìtọ́wò Ìwé Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìwádìí
  • Lẹ́tà
  • News
  • Oguso
  • Orin
  • Ọ̀rọ̀ Ìlú
  • Rìfíù Ìwé
  • Uncategorized