Òpóǹló ni mo wà tí mo ti máa ń gbọ́ nípa ìlú Èkó. Oríṣiríṣi ni atilẹ̀ máa ń gbọ́ ni ìgbà náà. Àwọn kan àtilẹ̀…
Ìbínú kò mọ̀ pé olówó òun ò lẹ́sẹ̀ ńlẹ̀. Ọ̀rẹ́ wa kan ló fi àṣejù kó bá ara rẹ̀ lẹ́nu ọjọ́ mẹ́ta yìí. Ó ń…
Àgbẹ̀ paraku ni Àkànó. Ìṣẹ́ àgbẹ̀ yí náà ni ó ń ṣe tí ó fi fẹ́ ìyàwó mérin tí ó wà ní ilé rẹ̀. Ohun…
Ọjọ́ tí mo ti ń fi àwo òyìnbó jẹun kò fọ́ mọ́ mi lọ́wọ́ rí. Ohun tí ènìyàn kúkú ń ṣe nìyí náà ní…
Inú títa ló jí mi. Mo tilẹ̀ kọ́kọ́ rò pé àlá tí mo lá ni ó fà á ni – èèyàn ò gbọdọ̀ jẹ ata…