Dèbórà, Obìnrin Ogun Ìmísí: Ìwé nípa ìgbésí ayé Àyìnlá Ọmọ Wúrà Ìwé tó kọ nípa a rẹ̀ kìí ṣé mímọ́ Bíkòṣe ti mímọ̀— Ìmọ̀ ogun.…
Orin: Ẹnikẹ́ni tí ìwọ bá nípa láti se ìrànlọ́wọ́ fún Òun náà lẹni kejì rẹ, tọ́jú rẹ. Ẹnikẹ́ni tó bá nípa láti ṣe ìrànwọ́ fún…
Ọ̀rọ̀ kan tí ń dùn mi lọ́kàn ọjọ́ pẹ́. Àsìkò tí tó wàyí tí n ó rò fáráalé. Ọ̀rọ̀ kan tí ń ṣe mí ní…
Aáyan ògbufọ̀ iṣẹ́ “Àbíkú” láti ọwọ́ Wọlé Ṣóyínká Asán, òfúútù fẹ́ẹ̀tẹ̀, aásà tí kò ní kán-ún ni gbogbo ìlẹ̀kẹ̀ tí ẹ fi dèmí m'áyé Èmi…
Kò sẹ́ranko bí kìnnìún níjù. Bó dolókìtì ẹni tí ó ṣe bí ọ̀bọ ò sí. Ẹranko tí ó sọ pé kí ìkookò ó dákẹ́ Wọ́n…
Apá Kiní Emọ́ kú ojú òpó dí Eésùn là, o là dànù Ọ̀pálánbá ọtí èèbó fọ́ Onígbá sọọ́ kò ri sọ Ta ń mọ bi…
Kíkorò Ewúro Gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Adùn ló yẹ kí ó gbẹ̀yìn ewúro Ṣùgbọ́n kò sẹ́ni tí ó ń Bèrè nípa kíkorò tí ewúro…
Akéwì Èmi lakéwì, mo lóyin létè. Mo kẹ̀tẹ̀ǹfẹ̀ ìmọ̀ Mo le sọrọ́ dòótọ́ bí n bá fẹ́! Bó wù mí, mo le sòótọ́ dòbu Ajá…
Moti dé'lé ayé ọjọ́ ti pẹ́, Moti d'ókè eèpẹ̀ ọ̀nà ti jì, Ṣebí ojúlarí ọ̀rẹ́ ò dénú. Ṣààsà ènìyàn ní fẹ́'ní lẹ́yìn táà bá sí…
Gbogbo ohun tí a bá ṣe lónìí, ọ̀rọ̀ ìtàn ni bó dọ̀la Gbogbo ayé ló máa tán Gbogbo wa la máa padà dìtàn. Nítàn kí…