Ẹ̀rọ Omi àti Ẹ̀rù | Mof’Ólúwawò O MojọláOlúwa
Ẹ̀rọ Omi Báwo ni ó máa ń rí l’ára nígbà tí o bá ń gbìyànjú àti gba ẹlòmíràn là tí […]
Ẹ̀rọ Omi Báwo ni ó máa ń rí l’ára nígbà tí o bá ń gbìyànjú àti gba ẹlòmíràn là tí […]
Ìwọ̀n ẹni là á mọ̀, A kì í mọ tẹni ẹlẹ́ni. Bí a ò bá ronú àti bùkèlè, Ó ṣe
Wón ní, Ikú ogun ló ń pa akíkanjú Ikú odò lo ń p’òmùwẹ̀ Ikú ẹwà ni wón ní ó ń
ÀKỌ́LÉ :Orí OHUN ÈLÒ: Ọ̀dà Ọìlì ỌDÚN : 2014/2015 ORÚKỌ AYÀWÒRÁN: Ọláòníye Àllíù Fèyíṣọlá GBÓLÓHÙN IṢẸ́ NÁÀ– Òrìṣà pàtàkì ni a mọ
[youtube]https://youtu.be/TzyREDaP3pU[/youtube] Ènìyàn Ènìyàn o, Ènìyàn yán Ènìyàn a b’ìdí yàn àn yán o Ènìyàn Òṣèlú, Ènìyàn ọ̀jẹ̀lú Ènìyàn tí ń