Òru là ń ṣèkà ẹni tó ṣe lọ́sàn-án kò fara rere lọ. Ilẹ̀ ti ta sí i ti àwọn ọmọ wòlìbísà tí ń ja àwọn…
Àkọ́lé Ìwé: Ìgbà Èwe (Childhood)Ònkọ̀wé: Emily R. Grosholz Olùtúmọ̀ sí Èdè Yorùbá: Kọ́lá Túbọ̀sùnỌdún Tó Jáde: 2021Olùtẹ̀wé: Ouida BooksISBN: 978-978-990-701-4 Ní ayé òde òní, ìgbéga…
Bí aré kò bá tó aré a kì í pòwe, bí ọ̀rọ̀ kò bá tọ́rọ̀ a kìí fìtàn balẹ̀, bí iṣẹ́ kò bá le a…
Olú ti d'ẹ́nu ní ìbúǹbú Ó di dandan kó jẹun. Ebi kìí wọnú kọ́rọ̀ míì ó wọ̀ ọ́ Òrìṣà bí ọ̀fun ò sí tipẹ́tipẹ́ Joojúmọ́ ní ń gbẹbọ lọ́wọ́…
À ṣé àwọn tí wọn ń pé Àlàmú l’Ájá kò sọ àsọrégè rárá. Bí ó tí lẹ̀ jẹ́ pé àbísọ rẹ̀ ni nítorípé àbíkú ni.…
Bàbá afọ́jú kan wà tí ó máa ń kọjá níwájú ilé wa nígbà tí mo wà ní kékeré. Ó dúdú àmọ́ irùngbọ̀n rẹ̀ funfun báláú.…
Ẹ forí jìn mí o, ẹ̀yin tí è ń gbé inú ilé yí. Ẹ̀rù ajá yín tí ó ń bà mí ni mo ṣe kọ…
Moti dé'lé ayé ọjọ́ ti pẹ́, Moti d'ókè eèpẹ̀ ọ̀nà ti jì, Ṣebí ojúlarí ọ̀rẹ́ ò dénú. Ṣààsà ènìyàn ní fẹ́'ní lẹ́yìn táà bá sí…
Gbogbo ohun tí a bá ṣe lónìí, ọ̀rọ̀ ìtàn ni bó dọ̀la Gbogbo ayé ló máa tán Gbogbo wa la máa padà dìtàn. Nítàn kí…
Ìyá kogberegbe, ní gbogbo ara àdúgbò mọ ó si, àmọ́ ìyá èkó ni àwọn ẹbí ń pè é. Kii dá rìn lai si ìyá Dupẹ.…