Ọjọ́ tí mo ti ń fi àwo òyìnbó jẹun kò fọ́ mọ́ mi lọ́wọ́ rí. Ohun tí ènìyàn kúkú ń ṣe nìyí náà ní…
Inú títa ló jí mi. Mo tilẹ̀ kọ́kọ́ rò pé àlá tí mo lá ni ó fà á ni – èèyàn ò gbọdọ̀ jẹ ata…
Kò sẹ́ranko bí kìnnìún níjù. Bó dolókìtì ẹni tí ó ṣe bí ọ̀bọ ò sí. Ẹranko tí ó sọ pé kí ìkookò ó dákẹ́ Wọ́n…
Kíkorò Ewúro Gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Adùn ló yẹ kí ó gbẹ̀yìn ewúro Ṣùgbọ́n kò sẹ́ni tí ó ń Bèrè nípa kíkorò tí ewúro…
Akéwì Èmi lakéwì, mo lóyin létè. Mo kẹ̀tẹ̀ǹfẹ̀ ìmọ̀ Mo le sọrọ́ dòótọ́ bí n bá fẹ́! Bó wù mí, mo le sòótọ́ dòbu Ajá…
Ẹ̀rọ Omi Báwo ni ó máa ń rí l’ára nígbà tí o bá ń gbìyànjú àti gba ẹlòmíràn là tí ìwọgan an wá di ẹni…
Ìwọ̀n ẹni là á mọ̀, A kì í mọ tẹni ẹlẹ́ni. Bí a ò bá ronú àti bùkèlè, Ó ṣe é ṣe ká jẹwọ móúnjẹ́.…