Ọ̀nà tí ó yá jù láti dá'ná sun ara ẹni Ni nípa fifi iná sí ilé ẹni. Òlùkọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì mi ló sọ wípé, Kí…
Olú ti d'ẹ́nu ní ìbúǹbú Ó di dandan kó jẹun. Ebi kìí wọnú kọ́rọ̀ míì ó wọ̀ ọ́ Òrìṣà bí ọ̀fun ò sí tipẹ́tipẹ́ Joojúmọ́ ní ń gbẹbọ lọ́wọ́…
Olóko ń sun kún Oní igba ewùrà ló nù ní ódẹ̀ òhun Ará ilé mi ní: òhun ò l'oko, bẹ́ẹ̀ l'òhun ò ká ewùrà. Ará…
ỌMỌ ÒRUKÀN Ikọ́ wíwú ológìnní kìí ṣàfiṣe Ìran baba wọn níí wúkọ́ fee. Gbígbó ajá kì í kúkú pajá. Ìran wọn ló ní gbígbó. A…
Ẹ̀rù àwọn ará ibí bà mí jọjọ. Ẹrù àìbìkítà wọn a máa ṣe mí bí ọyẹ́ ti ń ṣe ọmọ ìkókó. À ṣé ọdẹ tí…
Ṣóo wo iwájú tóò r’ẹ́nìkan O w’ẹ̀yìn wò, óò r’éèyàn L’ọ́tùn-ún l’ósì, ilẹ̀ tẹ́ lọ bẹẹrẹ Àṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, o ní ikú ló kàn Ọjọ́ a…
Kókó omi ó ṣé ta, Bẹ́ ẹ̀ ni ọ̀pá tín-ín-rín ọrùn yìí ò ṣé é fà. Ẹkùn inú aginjù yí wá di aláìléyíń, Ẹja rẹ̀…
Àgbà ọ̀pàpà paradà owó ará ìlú paradà ó dọbẹ̀ níkùn àgbà àgbà òṣèlú, àgbà ọ̀jẹ̀lú wọn jẹ̀lú jẹ̀lú, ìlú wó wọn jẹ̀lú jẹ̀lú, ìlú lu.…
Orí ire níí d'ádé owó Orùn ire níi s'èdìgbà ìlèkè Olóòtó ló ni ìgbádùn ayé Irú won ní sìí jè'gbádùn ayé L'élé báyìí ni oká…
Jòjòló akéwì tún dé Mo fẹ́ kọrin ewì sétí aráyé Ẹ yá mi létí yín. Ọ̀rọ̀ fẹ́ máa jábọ́ bí odi ẹyìn. Kí ẹ sáré…