Àtẹ́lẹwọ́

…ìràpadà, ìsọjí, ìtúntò

  • Ojúde-Àkọ́kàn
  • Ìgbàwọlé
  • Ewì
  • Àpilẹ̀kọ
  • Eré
  • Àwòrán
  • Ìtàn
  • Ìròyìn
  • Àṣàyàn Olóòtú

Ewì

Home /Ewì
Aáyan ògbufọ̀

Ìjẹ́ Abiyamọ Ní Àríwá Àti Ewì Mìíràn | Ayọ̀bámi Káyọ̀dé

October 9, 2021 0

Ìjẹ́ Abiyamọ Ní Àríwá/ Being a mother in the north Ìjẹ́ abiyamọ ni àríwá Mo máa ń lo ìgbà mi láti há Orúkọ àwọn ọmọdékùnrin…

Àṣàyàn Olóòtú

Èèmọ̀ Ní Pópó Àti Ewì Mìíràn|Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀

October 9, 2021 0

Èèmọ̀ Ní Pópó Ẹ wá wo ohun tí mo rí Ẹ dákun ẹ wá Ṣẹ̀ídà. Kàyéfì lohun tí mo rí A gbọ́ sọgbá nù A…

Àṣàyàn Olóòtú

Ọ̀kànlélọ́gọ́ta Ọdún Nínú Ìyà | Mustapha Sherif

October 1, 2021 0

Àrà mí ò rírí, mo rórí Ológbò látẹ Ajá wẹ̀wù, ó rósọ, ó tún gbọ́mọ́ dáni Èké dáyé, áásà dàpòmú Huuuuun kò jọmílójú Torí mo…

Àṣàyàn Olóòtú

Ṣé Òmìnira Nì Yìí? | Bakare Wahab Taiwo

October 1, 2021 4

A fẹ́ á jẹ máà fẹ́ á yó, Tó ń fúnni lóko ìdí ọ̀pẹ ro. Mo gbédìí fórílẹ̀-èdè, Tó sọ̀yà dohun àjẹsùn fáráàlú. Wọ́n fẹ́…

Àṣàyàn Olóòtú

Wèrè Alásọ àti Àwọn Ewì Míràn |Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀

July 26, 2021 0

Ta Ni Kí Ń Bi? Mo wò òréré ayé yíká Ayé ò yé mí rárá Mo wò sánmọ̀ lọ súà Kò yé mi bó ṣe…

Aáyan ògbufọ̀

Wíwá Ilé L’ájò |Adépọ̀jù Isaiah Gbénga

March 19, 2021 0

Ọ̀nà tí ó yá jù láti dá'ná sun ara ẹni Ni nípa fifi iná sí ilé ẹni. Òlùkọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì mi ló sọ wípé, Kí…

Àṣàyàn Olóòtú

B’ọ́bẹ̀ ẹ bá dùn àti ewì míràn | Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀

March 19, 2021 0

Olú ti d'ẹ́nu ní ìbúǹbú Ó di dandan kó jẹun. Ebi kìí wọnú kọ́rọ̀ míì ó wọ̀ ọ́ Òrìṣà bí ọ̀fun ò sí tipẹ́tipẹ́ Joojúmọ́ ní ń gbẹbọ lọ́wọ́…

Àṣàyàn Olóòtú

Màkàn Màkàn àti Àpọ́n |Ọlátúndé Àyìnlá

March 19, 2021 0

Olóko ń sun kún Oní igba ewùrà ló nù ní ódẹ̀ òhun Ará ilé mi ní: òhun ò l'oko, bẹ́ẹ̀ l'òhun ò ká ewùrà. Ará…

Ewì

Ọmọ Òrukàn àti ewì míràn | Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀

January 22, 2021 0

ỌMỌ ÒRUKÀN Ikọ́ wíwú ológìnní kìí ṣàfiṣe Ìran baba wọn níí wúkọ́ fee. Gbígbó ajá kì í kúkú pajá. Ìran wọn ló ní gbígbó. A…

Ewì

Jẹgúdújẹrá àti ewì míràn | Ayọ̀bámi Káyòdé

January 13, 2021 0

Ẹ̀rù àwọn ará ibí bà mí jọjọ. Ẹrù àìbìkítà wọn a máa ṣe mí bí ọyẹ́ ti ń ṣe ọmọ ìkókó. À ṣé ọdẹ tí…

Posts pagination

prev 1 2 3 4 … 7 next

ÀTẸ́LẸWỌ́

ÀTẸ́LẸWỌ́ jẹ́ àjọ tí ò wà láti gbé Yorùbá dìde àti láti tún iṣẹ́ Yorùbá tò. Àwọn àfojúsùn wa jẹ́: 1. Láti pèṣè ibi tí àwọn akẹ́kọ̀ ati ọ̀dọ́ leé máa kopa pẹlú oríṣiríṣi ẹya aṣa àti ìṣe Yorùbá látàrí ìdíje, ẹ̀kọ́, ìfọ̀rọ̀jomítoro ọ̀rọ̀ ati ṣi ṣe ìpàdé déédé. 2. Láti ṣe àgbékalẹ̀ ibi tí a ti má ṣe àkọsílẹ̀ ati ìpamọ òye àṣà Yorùbá ìgbà àtẹ̀yìnwá àti láti máá lo ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé fún ìdàgbàsókè àṣà wa. 3. Tí ta àwọn èyàn jí sí ìfẹ́ lítíreṣọ̀ Yorùbá latàrí ṣiṣe ètò ìwé kíkà, jíjẹ kí ìwé lítíreṣọ̀ Yorùbá wà nlẹ̀ fún tità àti ṣíṣe àtẹ̀jade àwọn oǹkọ̀wé titun ní èdè Yorùbá.


Contact us: egbeatelewo@gmail.com

  • Ilé
  • Nípa Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìdíje Ìwé Kíkọ
  • Ikọ̀
  • Àtẹ̀jáde
  • Ètò Ìwé Kíkà
  • Ògbóǹtarìgì: A Docuseries Project to Celebrate Old Veteran Yorùbá Authors
  • Kíni Wọ́n ń Sọ
  • Ètò
  • Ẹ kàn sí wa
  • Aáyan ògbufọ̀
  • Àpilẹ̀kọ
  • Àṣàyàn Olóòtú
  • Àwòrán
  • Eré
  • Ewì
  • Fídíò
  • Ìròyìn
  • Ìtàn
  • Ìtàn
  • Ìtàn Àròsọ
  • Ìtọ́wò Ìwé Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìwádìí
  • Lẹ́tà
  • News
  • Oguso
  • Orin
  • Ọ̀rọ̀ Ìlú
  • Rìfíù Ìwé
  • Uncategorized