Oore Ló Pé Oore ló pé Ẹ jẹ́ á ṣoore Ìkà ò pé Gbogbo Mùtúnmùwà! Bó o bá ṣe é ree Wà á kẹ́san À’tore…
Tata Àti Ìrẹ̀: Ẹranko Olóhùn Tó Bá Ìgbà Mu / On The Grasshopper And Cricket Ewì inú Ayé ò kú rí: Nígbà tí gbogbo ẹyẹ…
Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú / On Death Ọ̀rọ̀ Nípa Ikú I. Ǹjẹ́ ikú le è jẹ́ orun bí, kí ayé sì jẹ́ àlá? Kí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀…
Ẹ Fèyí Kọ́gbọ́n Mo délé Alárá N ò gbọ́ poroporo odó Mo délé Ajerò N ò gbọ́ kọ̀ǹkọ̀ṣọ̀ ajọ̀ Mo délé Ọwárọ̀gún-àga Bákan náà lọmọọ́…
Ó Di Pẹ́ Ǹ Túká Gẹ́gẹ́ bí a ti mọ̀ pé awọn ẹranko ló kọ́kọ́ dáyé ṣáájú àwa ènìyàn. Èyí jẹ́ kí àǹfààní wà fún…
Àlàmú Olókùn Ọ̀kan lára awọn ẹranko tí ó kéré jùlọ ni Aláǹtakùn (a-lá-rìn-ta-okùn-mọ́lẹ̀), bí ó bá ń rìn, yóò máa ta okùn mọ́lẹ̀, ìdí nìyí…