Òru là ń ṣèkà ẹni tó ṣe lọ́sàn-án kò fara rere lọ. Ilẹ̀ ti ta sí i ti àwọn ọmọ wòlìbísà tí ń ja àwọn…
Ta Ni Kí Ń Bi? Mo wò òréré ayé yíká Ayé ò yé mí rárá Mo wò sánmọ̀ lọ súà Kò yé mi bó ṣe…
Bí aré kò bá tó aré a kì í pòwe, bí ọ̀rọ̀ kò bá tọ́rọ̀ a kìí fìtàn balẹ̀, bí iṣẹ́ kò bá le a…
Ìlẹ̀kẹ̀ má jà á sílé má jà á síta ibì kan ni yóò já sí lọ́jọ́ kan. Dùnúnkẹ́ rẹwà lọmọ. Ó pupa bí àsáró elépo.…
Olú ti d'ẹ́nu ní ìbúǹbú Ó di dandan kó jẹun. Ebi kìí wọnú kọ́rọ̀ míì ó wọ̀ ọ́ Òrìṣà bí ọ̀fun ò sí tipẹ́tipẹ́ Joojúmọ́ ní ń gbẹbọ lọ́wọ́…
Jòjòló akéwì tún dé Mo fẹ́ kọrin ewì sétí aráyé Ẹ yá mi létí yín. Ọ̀rọ̀ fẹ́ máa jábọ́ bí odi ẹyìn. Kí ẹ sáré…
Ọjọ́ tí mo ti ń fi àwo òyìnbó jẹun kò fọ́ mọ́ mi lọ́wọ́ rí. Ohun tí ènìyàn kúkú ń ṣe nìyí náà ní…