Àtẹ́lẹwọ́

…ìràpadà, ìsọjí, ìtúntò

  • Ojúde-Àkọ́kàn
  • Ìgbàwọlé
  • Ewì
  • Àpilẹ̀kọ
  • Eré
  • Àwòrán
  • Ìtàn
  • Ìròyìn
  • Àṣàyàn Olóòtú

Tags archive: Poem

Home /Tag:Poem
Àṣàyàn Olóòtú

Káṣílẹ́sí  Pọlisì (Cash-Less Policy) | Akíntọ́lá Ismail Kọ́ládé

February 25, 2023 1

Ìlú kan gógó, Ilu òf'ara rọ Àwọn ará ìlú gaan ò rẹ́ẹ̀rín. Àṣe k'árówóná òdàbí k'álówó nílé k'álówó nílé gan-an òdàbí k’álówó lápò k’álówó lápò…

Àṣàyàn Olóòtú

Dèbórà, Obìnrin Ogun àti Ewì Mìíràn |Ìbùkúnolúwa Dàda

May 30, 2022 0

Dèbórà, Obìnrin Ogun Ìmísí: Ìwé nípa ìgbésí ayé Àyìnlá Ọmọ Wúrà Ìwé tó kọ nípa a rẹ̀ kìí ṣé mímọ́ Bíkòṣe ti mímọ̀— Ìmọ̀ ogun.…

Aáyan ògbufọ̀

Wíwá Ilé L’ájò |Adépọ̀jù Isaiah Gbénga

March 19, 2021 0

Ọ̀nà tí ó yá jù láti dá'ná sun ara ẹni Ni nípa fifi iná sí ilé ẹni. Òlùkọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì mi ló sọ wípé, Kí…

Ewì

Ẹni Àpọ́nlé L’abo|Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀

August 31, 2020 0

Ọ̀rọ̀ kan tí ń dùn mi lọ́kàn ọjọ́ pẹ́.  Àsìkò tí tó wàyí tí n ó rò fáráalé.  Ọ̀rọ̀ kan tí ń ṣe mí ní…

Aáyan ògbufọ̀

Àbíkú | Sùmọ́nù Ajíbọ́lá Adéjùmọ̀

August 19, 2020 0

Aáyan  ògbufọ̀ iṣẹ́ “Àbíkú” láti ọwọ́ Wọlé Ṣóyínká Asán, òfúútù fẹ́ẹ̀tẹ̀, aásà tí kò ní kán-ún ni gbogbo ìlẹ̀kẹ̀ tí ẹ fi dèmí m'áyé Èmi…

Ewì

Ẹ Bọ̀wọ̀ F’ágbà Àti Ewì Míràn|Àrásí Kamaldeen Moyọ̀sọ́rẹ

July 6, 2020 0

Ẹ Bọ̀wọ̀ F’ágbà “Ajá tó r’ólówó ẹ̀ rojú, kín ní ó f’ólówó è se kò tié yé mi.” —Éégunmọgají Àyìnlá Ọmọwúrà. Ìrírí kí lọmọdé ní,…

Àṣàyàn Olóòtú

Coro ló pojú kòró jẹ àti ewì míràn|Huswat Lawal

June 23, 2020 0

Coro ló pojú kòró jẹ Ṣebí láti ọjọ́ táláyé ti dáyé L'ayé tí ń yí, tí ọmọ adáríhunrun ti ń yí tẹ̀le. Àfìgbà tí Coro…

Ewì

Egbìrìn | Salawu Ọlájídé

June 3, 2020 0

Egbìrìn ọ̀tẹ̀ bí à ń ṣé pa ìkan ni ọ̀kan rú ní ìlú mi. Ní àgbàlá òdòdó yìí ẹ̀gún ń wù lára ènìyàn, Ìlú yìí…

Ewì

Orí | Akínyẹmí Muhammed Adédèjì

June 3, 2020 0

Orí l'atọ́kùn ara, Olóòótọ́ tí ń darí ìwà, Awakọ̀ ti kii sìnà l'ójú 'gbó, Orí mi gbé mi dé bi ire. Orí ni apẹja tí…

Àṣàyàn Olóòtú

À-pè-kánukò àti ewì mìrán | Táófíkì Ayéyẹmí

June 3, 2020 0

À-pè-kánukò Àpèkánukò! Àpèṣ'ẹnu ṣùùtì Bí-i músù ú rẹ́ja nínú ike. Owó ní í jẹ́bẹ̀, ìwọ ọ̀rẹ́, Bí kò bá sí nílé, Ẹ má wúlẹ̀ d'ọ́rọ̀…

ÀTẸ́LẸWỌ́

ÀTẸ́LẸWỌ́ jẹ́ àjọ tí ò wà láti gbé Yorùbá dìde àti láti tún iṣẹ́ Yorùbá tò. Àwọn àfojúsùn wa jẹ́: 1. Láti pèṣè ibi tí àwọn akẹ́kọ̀ ati ọ̀dọ́ leé máa kopa pẹlú oríṣiríṣi ẹya aṣa àti ìṣe Yorùbá látàrí ìdíje, ẹ̀kọ́, ìfọ̀rọ̀jomítoro ọ̀rọ̀ ati ṣi ṣe ìpàdé déédé. 2. Láti ṣe àgbékalẹ̀ ibi tí a ti má ṣe àkọsílẹ̀ ati ìpamọ òye àṣà Yorùbá ìgbà àtẹ̀yìnwá àti láti máá lo ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé fún ìdàgbàsókè àṣà wa. 3. Tí ta àwọn èyàn jí sí ìfẹ́ lítíreṣọ̀ Yorùbá latàrí ṣiṣe ètò ìwé kíkà, jíjẹ kí ìwé lítíreṣọ̀ Yorùbá wà nlẹ̀ fún tità àti ṣíṣe àtẹ̀jade àwọn oǹkọ̀wé titun ní èdè Yorùbá.


Contact us: egbeatelewo@gmail.com

  • Ilé
  • Nípa Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìdíje Ìwé Kíkọ
  • Ikọ̀
  • Àtẹ̀jáde
  • Ètò Ìwé Kíkà
  • Ògbóǹtarìgì: A Docuseries Project to Celebrate Old Veteran Yorùbá Authors
  • Kíni Wọ́n ń Sọ
  • Ètò
  • Ẹ kàn sí wa
  • Aáyan ògbufọ̀
  • Àpilẹ̀kọ
  • Àṣàyàn Olóòtú
  • Àwòrán
  • Eré
  • Ewì
  • Fídíò
  • Ìròyìn
  • Ìtàn
  • Ìtàn Àròsọ
  • Ìtọ́wò Ìwé Àtẹ́lẹwọ́
  • Ìwádìí
  • Lẹ́tà
  • News
  • Orin
  • Rìfíù Ìwé
  • Uncategorized